E se pupo oluso itan. Awon obaluje ni o wa ninu oselu ile wa, awa ara ilu lo kun won lapa. Awa ara ilu ti so otito nu. Awon odo oni ko fe rin ni ilana to too lati yan oko/aya. Ole, oju kokoro alapa ma sise ni lopolopo won. Awon odo oni ko fe ni ifarada ninu igbe yawo rara. Laziness lo nmu ki owu jije o po laarin awon igbe yawo. Iya/baba to ti lo sise lataro, se oun lo ma ri aye fun owu jije. Iya mi lo ma nsi ilekun fun ore binrin baba mi lati goke lo ba baba mi. Mo ranti pe, awon iya wa ati awon ore binrin baba wa jijo ma nlo ko ere oko. Ko si si ija..
Ese Olotu fun atuyewo itan yi Olohun abawa se alekun imo ati oye yin Amin ❤❤❤
God bless you Sir
Greetings from Ghana 🇬🇭
God bless you more sir 🙏🏾
Moun fi Akoko yi dupe fun Ile Ise yi ❤❤❤❤
Aanu Olohun Koni Kuro lodoyin Ooooo
Thank you, sir, for this educative and interesting story. God's blessings, sir❤
Thank you sir, may Allah continue to strengthen you.
This story is highly educative and appreciated
More wisdom and knowledge 🙏
More wisdom sir God bless you
Koni reyin Insha Allha❤❤
More Wisdom and Understanding Bihdinillahi Ta'Ala 🙏🙏🙏❤️❤️👍
Ese pupo fun atuyewo itan ilekun.
Awon ti wa ninu o selu ti aye ti ni si yin ojelu ni, won se oselu rara
Thanks so much sir ❤🎉
Elo ti Opo ni Awa maun ko
Ki Olohun ma se pada leyin yin Oooo
Opolo yin koni baje bijjah Rosullullahi (SAW) Eseun adupe olusotan wa ati gbogbo awon tejo nsise
Elabo sdupe aseyorio,mo ko eko gidi ooo
E se pupo oluso itan. Awon obaluje ni o wa ninu oselu ile wa, awa ara ilu lo kun won lapa. Awa ara ilu ti so otito nu. Awon odo oni ko fe rin ni ilana to too lati yan oko/aya. Ole, oju kokoro alapa ma sise ni lopolopo won. Awon odo oni ko fe ni ifarada ninu igbe yawo rara. Laziness lo nmu ki owu jije o po laarin awon igbe yawo. Iya/baba to ti lo sise lataro, se oun lo ma ri aye fun owu jije.
Iya mi lo ma nsi ilekun fun ore binrin baba mi lati goke lo ba baba mi. Mo ranti pe, awon iya wa ati awon ore binrin baba wa jijo ma nlo ko ere oko. Ko si si ija..
❤❤❤
Ope ni fun Oluwa lori ase yori ise yi .... lakayi wa koni Daru lase Oluwa
E se pupo Awon oselu ti si yin ojelu ni won se o baye je ni won afi ki olorun ko ko wa mo se
Ese pupo olootu
More wisdom sir
God bless you 🙏