Gbogbo ohun to wa lara mi ti ko faye gba iranlowo, o ya jade loruko Jesu, lara awon omo mi ti ko faye gba iranlowo, o ya jade, jade, jade jade loruko Jesu
Emi ati awon omo mi lo kan ni idile wa to maa laluyo loruko Jesu, Owo nla, ayo ile, ayo ilu oyinbo, ayo aseyori, ibukun oore gbogbo, aanu nibi gbogbo lorigun mereerin agbaye awon omo mi lo kan oo loruko Jesu
Ni oruko Jeeesu, Emi Mimo ooo, emi ti aye fi si mi lara lati da mi loro, ti won fi si awon omo mi lara lati da won loro, ni oruko Jesu, maa jade, jade, jade, loruko Jesu, jade jade, jade, emi idaloro maa jade loruko Jesu
I wish every Christian would connect to this channel and learn from baba’s wisdom
I and my son are connected to this morning prayer ijn....amen
More anointing and strength sir ijn... amen. Thank you sir
Daddy’s knowledge is incomparable,thank you daddy for blessing the world with your gifts.❤❤❤❤❤❤❤❤❤❤
I believe my day of joy has come.🙏
Gbogbo ofa awon tafatafa ninu ago ara mi ati ago ara awon omo mi, jade loni loruko Jesu, o ya jade, jade jade loruko Jesu
Gbogbo ohun to wa lara mi ti ko faye gba iranlowo, o ya jade loruko Jesu, lara awon omo mi ti ko faye gba iranlowo, o ya jade, jade, jade jade loruko Jesu
Halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah halleluyah
THANK YOU JESUS I AND MY CHILDREN WE RECEVIE ALL THE GOOD PROPHETIC THIS MONING
Ina ja mi gba tomotomo loruko Jesu
Nibi ti o le ti aye kan mi mo tomotomo, Owo Oluwa to le fa mi jade tomotomo fami jade fami jade, tomotomo fami jade tokotoko fami jade loruko Jesu
Emi ati awon omo mi lo kan ni idile wa to maa laluyo loruko Jesu, Owo nla, ayo ile, ayo ilu oyinbo, ayo aseyori, ibukun oore gbogbo, aanu nibi gbogbo lorigun mereerin agbaye awon omo mi lo kan oo loruko Jesu
I received d day of my joy no enemy's ca n be able to disturb me and my children, grand children in Jesus name. Amen
God bless Pastor Olajide!!! 😆
I love the way PATO usually messes with him! 😃
Olorun Aanu oo, gbemi pamo, ki aye ma baa gbemi pa tomotomo loruko Jesu
God will continue to bless and renew your strength sir baami and yours in Jesus name. Thank you sir.
Oluwa la ona abayo fun emi ati awon omo mi loruko Jesu
O Ye O Olorun, spot-on
Mo ri ara mi ati awon omo mi bo inu ibu agbayanu adura ti oni, mo gba gbogbo imuse ileri ohun rere fun aye mi ati awon omo mi loruko Jesu
Oluwa fa mi yo tomotomo nibi ti aye kan mi loruko Jesu
Oluwa fi aanu gbemi jade lari awon eniyan lasan ati alainilaari ti mo wa tomotomo loruko Jesu
Iwo ofa isina lara mi ati lara awon omo mi jade loruko Jesu, ofa isina, ofa oko eru, ofa ojukan, ofa ma ri alaanu loruko Jesu jade, jade jade, jade
I covered my prayer with blood of Jesus Christ
Oro mi ti dayo Loruko Jesu 🎉
Ni oruko Jeeesu, Emi Mimo ooo, emi ti aye fi si mi lara lati da mi loro, ti won fi si awon omo mi lara lati da won loro, ni oruko Jesu, maa jade, jade, jade, loruko Jesu, jade jade, jade, emi idaloro maa jade loruko Jesu
THANK YOU, JESUS
Amin Jeeesu
Amen
Gbogbo ofà idaduro Lara mi tomo toko olorun majemu ipe Abel Taiwo Ojo fina gbe jade patapata Lara mi tomo toko
Gbogbo ofà isina to nbe Lara mi tomo toko olorun majemu ipe Abel Taiwo Ojo fina lê jade patapata Lara mi tomo toko
Amin loruko Jesu
Gbogbo ohunkohun to nbe Lara mi tomo toko TI ko Faye gba iranlowo olorun majemu ipe Abel Taiwo Ojo fina gbe jade patapata Lara mi tomo toko
Gbogbo ofà awon tafatafa to nbe Lara mi tomo toko olorun majemu ipe Abel Taiwo Ojo fina gbe jade patapata Lara mi tomo toko
Gbogbo ebora adaniloro ninu aye mi tomo toko olorun majemu ipe Abel Taiwo Ojo fina gbe jade patapata Lara mi tomo toko
Amin Jesu
MORE ANOITHING SIR
72hours at where sir
Gbogbo EMI adaniloro to nbe ninu aye mi tomo toko olorun majemu ipe Abel Taiwo Ojo fina gbe jade patapata Lara mi tomo toko
Gbogbo EMI to nfi aye mi tomo toko sowo olorun majemu ipe Abel Taiwo Ojo
Amin jesu
Amin Jeeesu