TANI YIO PAROWA FUN TANIOLOUN LORI ORO ALH.ORIYOMI HAMZAT.

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 8 янв 2025

Комментарии • 60

  • @olwatoyinogundare8217
    @olwatoyinogundare8217 5 часов назад +3

    Igberaga po ju fun oriyomi kosi eni ti olorun olemuu ,ki olorun ma mu wa,thanks for the wisdom talk

    • @ire2020
      @ire2020 3 часа назад

      @@olwatoyinogundare8217 hmmmm e je ka ni Iberu Olorun, emi ori Oriyomi bi ẹní ti o ni igberaga sugbon mo ri bi ikọ ati irinju Ọlọrun. Ki lode ti olotitọ ki lẹni ni ọdọ awa yoruba? Ẹye fi ẹnu ba Alhaji Oriyomi je, iṣẹ ti Olorun fi ran lo njẹ oooo

    • @sulaimansanni849
      @sulaimansanni849 2 часа назад

      Se iwo o ni igberaga?

  • @thearcher2355
    @thearcher2355 2 часа назад +1

    Eku ise opolo..you are very right

  • @goilesanmi
    @goilesanmi 8 часов назад +2

    Many thanks for your POLITE and GENUINE advice to TaniOlohun etc.

  • @ire2020
    @ire2020 9 часов назад +4

    Ema fi oro Adedoyin we ti awọn oriyomi, iyatọ nla ni ooo.
    Won mo mo pa Timothy ni, igbesẹ ti won tin gbe ko dara rara. E jọwọ, e sọ otitọ ki ẹ ye gbe ika

    • @asaatiiseluyoruba1356
      @asaatiiseluyoruba1356  9 часов назад +3

      E logbo nkan to moso dada miofiwe rara sugbon ojo gate kojogate office ese mejeeji tile gate gate

    • @ire2020
      @ire2020 3 часа назад

      @asaatiiseluyoruba1356 sir, mo gbọ yin dada ṣugbọn Oriyomi ko se aburu lori Ọrọ Timothy, àwọn Adedoyin pa eniyan ti won si gbe oku e losi lai gbe ìgbésẹ to to. Ohun to sele si Oriyomi yatọ gidigidi ṣugbọn àwọn eniyan fe se Oriyomi ni ìbí titori otitọ to nṣe.

  • @ifeoluoluwatosin8211
    @ifeoluoluwatosin8211 15 часов назад +1

    Hmmmmmmn! Good advice baba miii!! Agba koni tan lorile ooo, yio ma ju yin se ooo. Aminnnnn

  • @ololadeAdeyemo
    @ololadeAdeyemo 50 минут назад +1

    Eku ohun,eku lakaiye opolo yin o ni daru mo ma ngbadun eto yin mo de nife si bi e se sakiyesi oro tani olorun ti e si gba ni imoran ki olorun ko je ko gba imoran titori tani olorun ti nta ese agere olorun koni je ki emi sise sise ba le amin

  • @remibejide
    @remibejide 7 часов назад +2

    This man is a proper Yoruba man.

  • @DemoMuideen
    @DemoMuideen 8 часов назад +2

    Confirm ni eso baba afiki olorun oba ko wayoo ooo❤❤❤

  • @OlukayodeHamzat
    @OlukayodeHamzat 15 часов назад +3

    Olohun o oba alaanu ni yin e fi aanu fi Oriyomi Okiki Omo Hamzat ati Naomi Olori ati principal e ma ri aanu gba aamin

  • @sunaderolake5888
    @sunaderolake5888 6 часов назад +1

    Baba, God bless you,,

  • @abiodunadigun3262
    @abiodunadigun3262 3 часа назад +1

    Well done sir, very inspiring message......

  • @MatthewOjo-mp7co
    @MatthewOjo-mp7co 8 часов назад +1

    Olorun a ko gbogbo mo'se. You have spoken very well. I share some of your thoughts and they are very germaine.
    Good one bro.

  • @sulaimansanni849
    @sulaimansanni849 2 часа назад +1

    Emi gan alara, mo mo igbiyanju ti mo se lori oro tani olorun.

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 15 часов назад +2

    Adura wa lo gbaa ooo.

  • @sulaimansanni849
    @sulaimansanni849 2 часа назад +1

    Baba, Eledumare ko ni gba lakaye yin ru.

  • @MARYAINA-g2s
    @MARYAINA-g2s 11 часов назад +2

    Good talk, Baba

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 15 часов назад +1

    Aaaameen ekaa lee sir. Aku ijoo meta ,an oo. Aku Alaa ja a odun oo. Emi wa ase pupo odun laaye oo. Aaaameen

  • @lindalondon-tz9sw
    @lindalondon-tz9sw 5 часов назад +3

    Tani olorun ko against oriyomi oo

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 15 часов назад +1

    Ikuuu ni ereee won lati odooo IBB.

  • @feliciaa3258
    @feliciaa3258 7 часов назад +1

    E ku lakaye baba

  • @mariamasiemasie8874
    @mariamasiemasie8874 6 часов назад +3

    Gbogbo awon olopa Nigeria to ma tele si protest ground before the day can't go to the event before it started, Omo Nigeria ema dibo fun awon ojelu mo.

  • @olwatoyinogundare8217
    @olwatoyinogundare8217 5 часов назад +1

    Thank you,esan nii, nkan to sefun agbala Gabriel nko

  • @AsibunaliArike
    @AsibunaliArike 8 часов назад +1

    efin taloloun sile olorun bo akukubin omo ni

  • @emmanueleniola9937
    @emmanueleniola9937 8 часов назад +2

    I REALY THANK YOU SIR FOR YOUR GOOD ADVICE FOR EVERY ONE TO BE POLITE ,FORGIVE ANG FORGET NO ONE ON EATH IS PERFECT.

  • @alaotijani6769
    @alaotijani6769 4 часа назад +2

    Yoruba nation no going back

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 15 часов назад +1

    Ogaaaa oooo.

  • @AyindeBusayo-s9t
    @AyindeBusayo-s9t 15 часов назад +2

    Otito leso baba beni eseun

  • @TundeGideon
    @TundeGideon 5 часов назад +1

    Opolo yin onidoba

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 15 часов назад +1

    Oro nla. Allah Akbar. Olorun oba obaa esan. Kabiesi eledunmare.

  • @AdegbolaMayowaJoseph
    @AdegbolaMayowaJoseph 5 часов назад +1

    Ejeki Ile ejo dajo

  • @lindalondon-tz9sw
    @lindalondon-tz9sw 5 часов назад +1

    Otito ni eso sir .

  • @abiodunolawoyin9774
    @abiodunolawoyin9774 6 часов назад +3

    Now what do u have to say about what does people said about him b4 he reacted,taniolorun only ananised the issues of oriyomi,n our opinion most not be thesame to a certain issues,he never asked anyone to locked him up,but said there should be investigation to prevent future ocurances,so why are u people coming for him,stop ur people from digging holes for others,cos they may eventually be the one to slumped in.

    • @olutoyiniyewandelawal9992
      @olutoyiniyewandelawal9992 6 часов назад +1

      You have explained this well. Tanioloun only wants people to look on both side of the coin.
      Also, those talking negatively to Tanioloun should talk wisely. Though two negatives does not make a right.

    • @abiodunolawoyin9774
      @abiodunolawoyin9774 6 часов назад

      Don't mind them jere,,while will u see the road,n still decided to work along the bush.

    • @asaatiiseluyoruba1356
      @asaatiiseluyoruba1356  5 часов назад

      Am not condemning his opinion but to educate him how to reciprocate others opinion

    • @abiodunolawoyin9774
      @abiodunolawoyin9774 5 часов назад

      @@asaatiiseluyoruba1356 , it's good,but those that also did there programs coming for him should stop,.

  • @ireneTadese
    @ireneTadese 10 часов назад +1

    Baba e se pupo e ku laakaye

  • @modinatsolomon7506
    @modinatsolomon7506 15 часов назад +1

    Allah Akbar

  • @bolaomoniyi1647
    @bolaomoniyi1647 7 часов назад +1

    You guys should stop blame governor,lpo governor o ri bi e se nro, to ripe oriyomi wa ogba owon ko tumo si pe gomina ko rira oriyomi, ti gomina o ba se bee awon ara oyo a koju ija si gomina. Oro naa gba ogbon

  • @topeadekola9522
    @topeadekola9522 2 часа назад +1

    I think tani olorun is saying the truth he did not say something against the oriyomi the truth is you people are only fighting for releasing of oriyomi with of laomi?

  • @christianahogundele2427
    @christianahogundele2427 7 минут назад

    Nkan ti o sele yi yato die si ti adedoyin ti kii ba se awon lo pa Timothy koni omo adedoyin salo fun ?

  • @jamesshall5160
    @jamesshall5160 7 часов назад +3

    Make sure you do your homework on Dangote because he is the biggest Philantropist in Africa with $1.2 Billion foundation! You said all these but you did not mention any of the 35 innocent kids that lost their lives, don't you think you are selfish? May be Tani Olohun was concern as a human being about the 35 kids while you ignored them but focus on Oriyomi.

  • @abiodunwilhelm5285
    @abiodunwilhelm5285 6 часов назад +1

    NI Ibo ni gbogbo eyin musilimi wa latigbati awon Alfa yin un bi awon BABANLA WA? E fi TALOLOHUN SILE! E jeki Ile ejo dajo Oriyomj Hamzat!

  • @olutoyiniyewandelawal9992
    @olutoyiniyewandelawal9992 6 часов назад

    Please look on both side of the law. I love Alhaji Oriyomi, and my heart feels heavy about his situation. Just as you've analysed, there may be the issue of Adedoyin in this matter. This is your analysis, also let give one a chance to rxpress themselves. You have spoken negatively to Tanuolun that his muslim nature has not left him. Being sentiment on this case is not the issue. Tanioloun only wants people to weigh both sides of the coin.

    • @asaatiiseluyoruba1356
      @asaatiiseluyoruba1356  5 часов назад

      TANIOLOUN have something against Oriyomi that's why I said he should forgive him and forget.

    • @sulaimansanni849
      @sulaimansanni849 2 часа назад

      Olonje iya ni tani olorun. Se e mo wi pe, owo ni awon ara ilu Ilorin fi tan tani olorun, ni o je ki o di ero ewon. Ki i se wi pe, o fe gba Ilorin lowo awon Fulani. Tori owo ni.​@@asaatiiseluyoruba1356

  • @leahayodele2526
    @leahayodele2526 5 часов назад +1

    THANK BABA AS A YORUBA NATION MAN I DON'T THINK ..TANI OLORUN IS IS RUBISH....I CONDEMNED TANI OLORUN..HE TOO MOUTHY.

  • @ayodejiolatoregun3926
    @ayodejiolatoregun3926 8 часов назад +1

    What rubbish areyou talking.

  • @olanrewajulanre8235
    @olanrewajulanre8235 6 часов назад +1

    Great talk Baba but IBB he isn’t our baba o

    • @asaatiiseluyoruba1356
      @asaatiiseluyoruba1356  5 часов назад

      Am trying to teach someone how to respect elderly people.thank you