O TI SELE O, E WA GBO TUNTUN O OMO YORUBA.

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 27 сен 2024

Комментарии • 15

  • @adeolaosho3431
    @adeolaosho3431 2 дня назад +3

    Ibukun nifun orile ede yoruba

  • @adekoyamichael6909
    @adekoyamichael6909 День назад +1

    Igbe aye odale ati agbehin beboje o n ja awa omo Yoruba logun.
    Iwa ote, rikisi ati iwa maa tomi majumi.
    Ki a ta ara ile eni lopo fun alejo.
    Omo Yoruba le e pa omo iya omo baba a won fun alejo.
    Bi omo Yoruba se ni ogbon to gege bi omo ile Oba, bee ni aago omugo si tun n yo omo Yoruba lenu.
    AYAFI KI OLORUN JOWO GBA ORILE EDE E YORUBA A WA FUN WA, ALAFIA NI FUN GBOGBO AWA OMO YORUBA NI TILE TOKO

  • @victoriajones4900
    @victoriajones4900 2 дня назад +2

    EYIN NANI

  • @BamideleMathew-tg6pe
    @BamideleMathew-tg6pe 2 дня назад +1

    Undiluted facts.
    Thank you and God bless you baba wa Omoluka.

  • @OmitogunDennis
    @OmitogunDennis День назад +1

    Well done 👍. E ku ishe o 🎉. Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.

  • @adeolaosho3431
    @adeolaosho3431 2 дня назад +1

    Yoruba nation nikan soso lona abayo .

  • @BabatundeIbrahim-jd2ff
    @BabatundeIbrahim-jd2ff 2 дня назад +1

    Yoruba nation is really no going back

  • @adeolaosho3431
    @adeolaosho3431 2 дня назад +1

    Yoruba nation no going back .

  • @kabirballey3428
    @kabirballey3428 День назад

    Bi oni Christian ba ma iwun ti IFA so KO buru rara nigbayęn omo yoruba koni le fi sonu nio

  • @kabirballey3428
    @kabirballey3428 День назад

    Awon Christian won o KO fę rara ki ęniti owa ni inu chriteniti won dę fę ki won tun wa iman kankan lo si iwaju rara nitori kini ki oju won ma ba la

  • @kabirballey3428
    @kabirballey3428 День назад

    Awon Christian won o KO fę rara ki ęniti owa ni inu chriteniti won dę fę ki won tun wa iman kankan lo si iwaju rara nitori kini ki oju won ma ba la

  • @kabirballey3428
    @kabirballey3428 День назад

    Awon Christian won o KO fę rara ki ęniti owa ni inu chriteniti won dę fę ki won tun wa iman kankan lo si iwaju rara nitori kini ki oju won ma ba la

  • @olayinkaokanlawo1561
    @olayinkaokanlawo1561 2 дня назад

    God forbid oo

  • @OlarinwajuStephen
    @OlarinwajuStephen День назад

    Correct

  • @iretiebiesuwa9071
    @iretiebiesuwa9071 2 дня назад

    God bless you my brother