Aare, E ku ise opolo, E ma ti ma daruko enikeni, tabi iran kan, ki oro na ma ba da wahala sile.. ise ni won se ibi ti olukaluku ba si mo de ni yoo se de...
But the story still continues coming out in January may be they will explain more about lisabi and his relationship with the recent king. Thank you for all you do sir
Ẹ kú Ojúmọ́ o Ààrẹ Òpìtàn ilẹ̀ Ibadan. Àkíyèsí , àwọn ajẹlẹ máa jẹ aiye ìjẹ kujẹ ó. Títí tó fi de England lọdọ àwọn gẹ̀ẹ́sì ni ajẹlẹ tí máa kọ́kọ́ bá ìyàwó tún tún sún kí ọkọ rẹ̀ oto bá sún. A lọ ká ìwé "Brave Heart" or sinima ẹ.
Aare opitan, eni Ibrahim chatta ki se yoruba pe tapa ni, sugbon ninu video yin kan, eni lenpe ni awon tapa, ati wipe asekubo awon offa niwon. Bawo wa ni tapa ki se se Iran yoruba mo abi awon offa ki se yoruba Mo ni ?
Weldon sir
ile Yoruba oni baje

I’ve been expecting your review
But your voice is low at the beginning👍👍
Mansa allah 💯
Eseun gan Onibode
Ẹ kú Ojúmọ́ o Ààrẹ Òpìtàn ilẹ̀ Ibadan. Àkíyèsí , àwọn ajẹlẹ máa jẹ aiye ìjẹ kujẹ ó. Títí tó fi de England lọdọ àwọn gẹ̀ẹ́sì ni ajẹlẹ tí máa kọ́kọ́ bá ìyàwó tún tún sún kí ọkọ rẹ̀ oto bá sún. A lọ ká ìwé "Brave Heart" or sinima ẹ.
Aree opintan Ile Yoruba,eku eto
Oluwo is using you people to cash out....... Oluwa ti gbe islam ni goal goal 😂😂
Aare opitan, eni Ibrahim chatta ki se yoruba pe tapa ni, sugbon ninu video yin kan, eni lenpe ni awon tapa, ati wipe asekubo awon offa niwon. Bawo wa ni tapa ki se se Iran yoruba mo abi awon offa ki se yoruba Mo ni ?
Good point. I think what he meant is Yoruba Oyo, not the general Yoruba
Why can't this celebs make proper findings before acting real life stories, if its a real life stories, there is nees to to make proper findings