Ibi tí ikú bá ti kanimo ibeena ni aiye mọọ, èèyàn òsì kí ń lọ sí ọ̀run re tuba, ni ilé aiyé laa gbé pìwà dà, Chief Mosinud Olanrewaju Adepoju Akanmu baba Adejare od'igba, ka pàdé pẹ̀lú ayọ̀ tí ó bá di ọjọ gbende
Bi a se ri ni yen o! Sugbon ki ni a fe se bi ko se ki a gbe Orin yin fun Oba A So, Oba a f'ase d'epe nu? Ope ati Iyin ni fun Mimo-Mimo ni Igbesi Aye Baba.
Baba wa ! Olanrewa Adepoju 🕊️😭🕊️ Sun ree o... Olotito eniyan
@@Omoayo7066 🙏🏾🙏🏾🙏🏾
We lost a great Yoruba Talent Man. May your soul rest in peace Baba.
@@larrywillow5934 We certainly did.
Baba daada sun re o ibi lefi adagba aye rosi lailai ni iranti olododo
Ibi tí ikú bá ti kanimo ibeena ni aiye mọọ, èèyàn òsì kí ń lọ sí ọ̀run re tuba, ni ilé aiyé laa gbé pìwà dà, Chief Mosinud Olanrewaju Adepoju Akanmu baba Adejare od'igba, ka pàdé pẹ̀lú ayọ̀ tí ó bá di ọjọ gbende
Be ni o. Ajoji ni gbogbo wa je l'aye. Ko si Ariku yeri ninu gbogbo wa.
Rest in perfect peace. Good man.
Orun rere oba apede, masun laya oluwa re
E seun.
Rest in Peace ✌️
@@murainakehinde3395 🙏🏾🙏🏾🙏🏾
Kasa! Yoruba land lost another icon
Bi a se ri ni yen o! Sugbon ki ni a fe se bi ko se ki a gbe Orin yin fun Oba A So, Oba a f'ase d'epe nu? Ope ati Iyin ni fun Mimo-Mimo ni Igbesi Aye Baba.
Oruko rere sanju wura ati fadaka lo. Awon obayeje eniyan, alo kolohun kigbe ogara olosa onijibi, ero nu piwada
Oníjìbìtì edit
This is a good man
Yes, he was. Although his legacy still lives on. And will live on for generations to come.
Rest in Peace
E seun.