Konii yewon,awon tiko fe ki naija dara niyen. Gbogbo won maa sofo danu ni. Se ki a maa gbe epo tiwa lo si ilu won lati maa fopo ki won tun maa taa pada funwa. Ota itesiwaju ni gbogbo awon munileru wonyi. Greater Dangote!! That's why ti refinery naija kose sise nigbati awon oloriburuku olojelu wa ti gbabode funwa. Asiko to ki gbogbo awon ipinle to ni epo se ile ifopo tiwon ki oju Lee ti awon obayeje,apanilekunjaye wonyi.
Won Sese bere ni, it's no longer as business as usual. Things must change. God bless Nigeria.
God bless DUNGOTE🙏god bless Nigeria 👏❤️
Olohun alanun julo o lu toju gbogbo eda
Ko bamin duro ti Dangote o
Won sese bere ni o
But fuel ⛽ price as no come down in Nigeria now
But still price of fuel in Nigeria is high
Konii yewon,awon tiko fe ki naija dara niyen. Gbogbo won maa sofo danu ni. Se ki a maa gbe epo tiwa lo si ilu won lati maa fopo ki won tun maa taa pada funwa. Ota itesiwaju ni gbogbo awon munileru wonyi. Greater Dangote!! That's why ti refinery naija kose sise nigbati awon oloriburuku olojelu wa ti gbabode funwa. Asiko to ki gbogbo awon ipinle to ni epo se ile ifopo tiwon ki oju Lee ti awon obayeje,apanilekunjaye wonyi.
Let the game change. We need to be a producing and not a dumping ground
Yíó Dí-ròrùn fúnwa jálè 🙏
Orí wọn burú, wọn ṣẹṣẹ bẹrẹ ni
Ko ni ye won awon oloribu ti won ba oro aje wa je na ni ye
Won o ni bo nbe
The Lord is good, God bless.
Kiwon ma mun now
Labarina
God is good always tinubu is working well we believe in him
Awon olote ,sebi awon omo Nigeria lo loko ile ifoepo na SI ile okeeree , kilode ti arawa untawon bayi ?
Olohun alanun julo o lu toju gbogbo eda
Ko bamin duro ti Dangote o
Won sese bere ni o