A MA FI AROKO OGUN RANSE PADA SI EMIR ILU ILORIN

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 16 окт 2024
  • LAIPE LAIJINA AWA TA NILE BO WA GBA

Комментарии • 41

  • @OmitogunDennis
    @OmitogunDennis 6 дней назад +1

    E ku ishe o 🎉. Awon Alale yio gbe wa o 😊. Up Yoruba Nation ❤. No going back 😮.

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 7 дней назад +2

    Ekuirore Oooo AROLE OMO BABA 10 10 eku eto OLORUN OBA a ma wa pelu yin laseeedumare 🙏🙏🙏

  • @sanitempleprayer472
    @sanitempleprayer472 7 дней назад +2

    Wontifi adua Alkuran ko omo yoruba laya je atipe kosenikan tofe gbowo kale fi ra nkan eelo tolagbara sugban ki oluwakogbawao Amin

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 7 дней назад +4

    I am a good Muslim, nation has nothing to do with religion,
    Gbogbo Omo Yoruba,omo iya mi ni won

  • @abiodunawonowo1157
    @abiodunawonowo1157 7 дней назад +2

    God bless YORUBA NATION. YORUBA NATION is the only solution. It is well with YORUBA NATION.

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 7 дней назад

    A Rogun yo ni YOruba welldone our Brother ohun ti won ba gbe wa ohun ni won ma gba pada won a gba.

  • @LewisMuturi-b7u
    @LewisMuturi-b7u 7 дней назад +2

    Olori elesin ajeji ni o wa ni Ilorin oooo, ko si OBA ni Ilorin ooooo

  • @usmanwahab6262
    @usmanwahab6262 7 дней назад +2

    Awon Ilorin n gba abode fun Nile Yoruba tipetipe, sugbon olorun o si leyin alabosi

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 7 дней назад +1

    ASE ASE ASE Edunmare ASEWA 👍

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 7 дней назад +3

    KI WON bere lati Ori kewa titide Ori OGUN won a ri itan Abraham ni be, nitori Lehin iku Omi ni won bi Abraham Iran NOA. Ni Abraham ooooooo

  • @francislade85
    @francislade85 7 дней назад +1

    Olorun Olodumare yio fun e ni agbara.

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 7 дней назад

    E jo e ba wadi odun wo ni bi Anobi,odun melo lo se laiye ati odun to ku

  • @vickyyorubanationnownogoin8787
    @vickyyorubanationnownogoin8787 7 дней назад

    🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤣🤩🤩🤩🤩🤩🤩🤩🤩🤩🤩🤩awon Aalfa ko ke o won n’ngbo bi Aja ni

  • @francislade85
    @francislade85 7 дней назад +3

    Lagbaji, ki se Omo Yoruba

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 7 дней назад +1

    Ododo Oro ni AROLE ODUDUWA nu so ooooo gbogbo e yin ODALE OBA gbogbo yin la ma pare patapata.

  • @AmosAdesina-o7v
    @AmosAdesina-o7v 7 дней назад +1

    Moti so tipetipe pe alabode ni awon ilorin ooo

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 7 дней назад

    Gbogbo eyin IMAM igbadi o wa lara yin ifunpa o wa lara yin,Ado o wa ninu lawani te we sori pelu ijapa kekere gbogbo awon hausa a ri ifunpa lapa won ki le ww nso pe olorisa lawon kan . Eyin Afa e nte yanrin ki le wa nso

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 7 дней назад +1

    AROLE ODUDUWA E ba mi so fun MASBABA ATI OLOWO EKO pe ki won fun awon Alfa yen pe ki won lo ka IWE GENESIS won a ri ITAN Abraham ni be

  • @AdeyinkaEbenezer
    @AdeyinkaEbenezer 4 дня назад

    ❤❤❤❤❤❤❤

  • @tinaparker5248
    @tinaparker5248 7 дней назад

    Leave foreign religion alone and embrace your own 😊
    Yoruba nation now ❤❤❤❤

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 7 дней назад

    Se awa le lo si ile hausa ka lo gba ile won.

  • @banjiwilliams4394
    @banjiwilliams4394 7 дней назад

    EFI WON SILE ODUN MO AWON YORUBA ILORIN KI AWON FULANI MAJE OBA NI ORI WON ODARA BE FUN WON

  • @modupeolotu2918
    @modupeolotu2918 2 дня назад

    Werey ni gbogbo yin alakatakiti imam ile Yoruba, sugbon ojise yin ko yin ki e ma pa eniyan ti ko ba se esin ajoji yin, ti e ba ti pa eniyan e wa pada ma mu oti lile ati opolopo omo obinrin ko ti balaga, se eri pe e ti werey.

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 7 дней назад

    Se bi a tunmo Bibeli si yoruba by Samuel Ajayi crowder ko si ese ti won ba tunmo si yoruba.

  • @stellaodele5734
    @stellaodele5734 7 дней назад

    Gbogbo obinrin to wa nse ajo lodo won nse ni won mba won sun se ise Afa ni yen

  • @francislade85
    @francislade85 7 дней назад +1

    Arole baba 1010, Olorun Olodumare, Olorun akoda, iseda sile Yoruba ATI Oduduwa won a ti e lehin lati ja ajaye.

  • @imoleadini
    @imoleadini 7 дней назад

    Eripoponu.ponile yoba.awon eleribu.niwon awon.oponupo ninu.awon alfa.inaniyin enulasan ijekuje.niojegbadun oleniyun emike alkuriani.amo opolopo awon.alfa ole.alainikanse enu.lasan biajakara lasan loriro nigbogbo.ntenso edakun.esenu botiwaenudun juyo

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 7 дней назад

    ODEY ni e ologbeni oni sokuso AROLE OMO BABA 10 10 e ma ma Fi oju won han mo jare nitori ti e ba n Fi oju won han e n promote won e stop se be

  • @Adedayosalako-vu3cv
    @Adedayosalako-vu3cv 7 дней назад

    He Is not Oba but Emir, ordinary Baale under sultan of Sokoto.

  • @Fjjc-s6w
    @Fjjc-s6w 5 дней назад

    Iwo Alufa yi olojùti rara Ori awon Muslims egbe re ni Ile hausa ti won dunbu enia ti won ke alarkibaru lo moju to yen ki o fi awon elaborate sile se kosi elabo ninu ebi re

  • @waleikujuni9463
    @waleikujuni9463 7 дней назад

    Please don’t address him as Oba. He is Emir which is equivalent to Baale

  • @ModupeolaBello-zi2yw
    @ModupeolaBello-zi2yw 7 дней назад

    ODEY oponu ni ma niyen afoko gbe ko mu

  • @frankbolarinwa8062
    @frankbolarinwa8062 7 дней назад +1

    This man is mad, Isese has ever being in existence before either Christianity or Islam, so he is talking rubbish.Let him go and study his Quran very well, where Quran mention Orunmila, Sango, Ogun, Obatala and Osun are messenger of God.

    • @BosedeAdesanwo
      @BosedeAdesanwo 6 дней назад

      Before Christianity and Islam was brought to Africa , before slave trade, our forefathers have what they worship