That story about Bode Thomas was true. I checked it on Google. I appreciate the Obas for their wisdom. May bad history never repeat itself. The story is scary.
O npe ki Obasanjo to kan awon Oba l'abukun. Ohun ti Oloye Sunday Igboho nja fun niyen, wipe ki Ase pada sodo Awon Oba ile Yoruba sugbon awon Oba yi naa ni won gbabode fun Oloye Sunday Igboho. Awon Oba wa ko se anfani kankan fun wa ni ile Yoruba.
Alale ile Yoruba lo fi awon Oba ile Yoruba se esin ni gbagede...owo lo wo won mole..malu lo lu won pa .eleda sunday Adeyemo lgboho koni je ki awon Oba ile Yoruba gbayi mo ni agbara Olorun ase Edumare.....
Gbogbo Yoruba nwo asise Obasanjo ti kosiye Lori been. Mofe ki a mo wipe eni to see nkan to dunni loni, lese nkan to ma dun moni Lola.Efi ori Jin Obasanjo fun asise to see.
Saa ba daa. Awon oba yen ti lo. Bo ya lo la ale ri iru won buti lo wo lowo lowa baa yi. Koo si. And won dee so roo sii o. Beeni. Itan Bode Thomas. Ogaa ju.
hello sir awon oba ti ko iyan ara won kere nipa riba gbigba owo aito eyin ewo yoruba nation bi iya tinje awa omo Yoruba tipe tipe ose ni lanu pe awon ausa toje bara ni awon fulani bawo ile awa yorubu to jepe baba wa awolowo ni won ko aso fun won sugbon won pada wadi enito sowa di eru won eyin oba eko dasi titi gbogbo nkan fibaje tan
I know this man will surely exceed his knowledge. Can you please tell us who and who among the Yoruba leaders that sat alongside to write Nigeria's constitution?
Ìbéérè náà ni pé, àsìkò wo ni Obásanjó dòbálè fàwon Oba? Sebí ìgbà tó fé dupò president ni ó lo ń dóbálè káàkiri. Bàbá Kólá Olóòtú, e so ìtàn lónà tó pé. Àgbààyà lobásanjó. Síò!
No kise igbati ofe du po president. Igba installation present Ooni lo dobale, O tun losi warri otun dobale fun young Oba Warri. Igbati otun losi Ketu Badagry o dobale fun Alaketu, O tun dobale fun Obas ni Abeokuta. I think he intentionally wanted to do what he has done.
There's a street called Bode Thomas, too, in Palm groove, very close to Professor Pela' house. As a matter of fact, you can get to Bode Thomas through Onipaanu.
OMO ALE ODALE OPONU OLORIBURUKU NI BABA YI . HE IS AN IBO MAN AND THAT'S WHY HE WANTED TO GO BACK TO IMO STATE. WHATEVER DO YOUR LOOT HOUSES YOUR LIBRARY BELONGS TO THE ABEKUTA PEOPLE.
Which apology? You guys should all go and sit down! Who are the Ọbas? When Tinubu refused to stand for Ooni of Ifẹ̀, at Elegusi's party, he just offered him a handshake! What happened to Tinubu? OBJ belongs to the Yorubas that doesn't take shit or nonsense! So many useless Yorubas have lost it to atẹnujẹ & ọ̀tẹ̀!
Mogaji God bless you. Your wisdom is well praised - long life Oba-lola.
Thanks Sir for your intelligence and analysis towards issues,may you live long Sir.
That story about Bode Thomas was true. I checked it on Google. I appreciate the Obas for their wisdom. May bad history never repeat itself. The story is scary.
You are more than where you are, we need you as leader, God will put you there.
This is beautiful, with the way you analyzed the story of Bode Thomas. Weldone sir!
God bless you real good sir. You are very intelligent sir. I love you sir
Thanks sir ,ur statement s are very good, God bless u sir
O npe ki Obasanjo to kan awon Oba l'abukun. Ohun ti Oloye Sunday Igboho nja fun niyen, wipe ki Ase pada sodo Awon Oba ile Yoruba sugbon awon Oba yi naa ni won gbabode fun Oloye Sunday Igboho. Awon Oba wa ko se anfani kankan fun wa ni ile Yoruba.
😂😂😂 you are very right.
May you live long, to become the olubadan❤❤
Baba you are Too special Sir The story you prevail is true sir thank you so much for this job sir
God bless you sir🎉
Owo ati Malu ti gba ase lenu awon odale Oba ile Yoruba
Bode Thomas is in western Avenue going to iponri in surulere Lagos state.
This is the truth bless you
Baba kola Olotu, God bless you
Baba Mogaji, e ku ise opolo emi yin a gun lagbara Eledumare
His true stroy of Alafin and Bode Thomas
Opolo yin koni doba Baba Kola Olootu!
This is never a mistake
It's deliberate
Se bi😊 igbo ni Baba Obasanjo, won gbodo bi inu si won.
Gaskiya
Hmmm Oba ni Awon Alaafin koti si baba Walahi
Alale ile Yoruba lo fi awon Oba ile Yoruba se esin ni gbagede...owo lo wo won mole..malu lo lu won pa .eleda sunday Adeyemo lgboho koni je ki awon Oba ile Yoruba gbayi mo ni agbara Olorun ase Edumare.....
Kings in general
Not just Yoruba
Walahi 😂😂😂
Gbogbo Yoruba nwo asise Obasanjo ti kosiye Lori been. Mofe ki a mo wipe eni to see nkan to dunni loni, lese nkan to ma dun moni Lola.Efi ori Jin Obasanjo fun asise to see.
Beeni eri mi pa. Baba Kola Olotu. Olorun o. Esan wo omo goo bi a ti n se isomo lo ku ru ko o.
You are right brother
You are highly intelligent, I love you sir.
Good talk
He is naturally Pompous!!
Saa ba daa. Awon oba yen ti lo. Bo ya lo la ale ri iru won buti lo wo lowo lowa baa yi. Koo si. And won dee so roo sii o. Beeni. Itan Bode Thomas. Ogaa ju.
Obasanjo de, eemọ w'ọlu o
You are highly right.
Thanks
hello sir awon oba ti ko iyan ara won kere nipa riba gbigba owo aito eyin ewo yoruba nation bi iya tinje awa omo Yoruba tipe tipe ose ni lanu pe awon ausa toje bara ni awon fulani bawo ile awa yorubu to jepe baba wa awolowo ni won ko aso fun won sugbon won pada wadi enito sowa di eru won eyin oba eko dasi titi gbogbo nkan fibaje tan
I know this man will surely exceed his knowledge. Can you please tell us who and who among the Yoruba leaders that sat alongside to write Nigeria's constitution?
Chief Rotimi Williams was among the prominent lawyers that drafted the Constitution
Opolo yin o ni daru sir
Radarada ni eyin ma nso
Won ki fi agbalagba pin Iku
What's the function and duty of Oba today?
The governors already taken over
The British constitution scraped them off
Zero😂😂😂
E ku oro opolo ati ogbon ori
There are too many obas in Yorubaland. We need to prune them down.
This is true
Won ki fi Agbalagba pin OGBON
Kola olotu agba oje kie pe Lori eepe
That was 1953, November 22 - 23 Bode Thomas
Ìbéérè náà ni pé, àsìkò wo ni Obásanjó dòbálè fàwon Oba?
Sebí ìgbà tó fé dupò president ni ó lo ń dóbálè káàkiri.
Bàbá Kólá Olóòtú, e so ìtàn lónà tó pé.
Àgbààyà lobásanjó. Síò!
I’m not in support of Obasanjo oo
But he actually prostrated for kings after he was even president
No kise igbati ofe du po president. Igba installation present Ooni lo dobale, O tun losi warri otun dobale fun young Oba Warri. Igbati otun losi Ketu Badagry o dobale fun Alaketu, O tun dobale fun Obas ni Abeokuta. I think he intentionally wanted to do what he has done.
@@debraolufunlalemi7826 Ìyen dáa.
It’s a wake up call for the Yoruba Obas.
Dr CSI called them several times but they didn’t answer.
@@debraolufunlalemi7826 yeah
Walahi FACTS. Ogboo ku bi ajaa ni.
Baba Surulere ni bodi Thomas wa ni Adugbo mi ni Akerele side
Bode Thomas Street is also in palm Grove near Onipanu
Alaafin was doing with NCNC party which belong to Azikuwe
Bode Thomas is in Surulere not Palm Grove
Eleyii koja mistake. For ordinary Man to command first class Kings like primary school pupil.
But Northern Emir they're not doing such a thing to this character
Exactly, obasanjo too,cant fo that over there
Suru-lere Ni Bode Thomas wa leko, kii se palm groove.
There's a street called Bode Thomas, too, in Palm groove, very close to Professor Pela' house. As a matter of fact, you can get to Bode Thomas through Onipaanu.
Hello my Dear, there is another Bode Thomas in Palm groove, by Shylon.
Ibadan o do
Baba kola olotu e funra
It's not right in any culture (not only in Yoruba) in Nigeria to say kings should stand for you.
WON TO FI JE SHAWARMA ATI AYAAMAMAASE PLUS WITH RICE.
You make mistake sir, alafin adediran was adeyemi 2 not first Sir
E se Sir , e ku eto
Idobale iro eleyi lafi mo
There is another Bode Thomas Street in Surulere. It runs off Western Avenue to Babs Animashaun.
Why ti won fi maa gbe ?, he was doing the right thing then.
OMO ALE ODALE OPONU OLORIBURUKU NI BABA YI . HE IS AN IBO MAN AND THAT'S WHY HE WANTED TO GO BACK TO IMO STATE. WHATEVER DO YOUR LOOT HOUSES YOUR LIBRARY BELONGS TO THE ABEKUTA PEOPLE.
No he need to apologize, else we will keep on disgracing him
Which apology? You guys should all go and sit down! Who are the Ọbas? When Tinubu refused to stand for Ooni of Ifẹ̀, at Elegusi's party, he just offered him a handshake! What happened to Tinubu? OBJ belongs to the Yorubas that doesn't take shit or nonsense! So many useless Yorubas have lost it to atẹnujẹ & ọ̀tẹ̀!
N who are you to disgrace a whole formal president of federal republic of Nigeria???
OBASANJO to apologise?...you go wait tire
No respect fun awon oba ile yoruba now,ki olorun fi orijin Alafin of oyo obasanjo kotobe
40 40 times
Iro nta wa ra waa ra ni sir.