Ẹ YE BA ITAN WA JE

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 2 янв 2025

Комментарии • 23

  • @MikhailAwolowo-zm7fr
    @MikhailAwolowo-zm7fr 2 месяца назад +4

    Alfa yi ati awon janmo re ni oye ki a maa pe ni, obo ngbe obo gun ope.

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 2 месяца назад +2

    Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí wọn jẹ́ Gomina wa ni ilẹ̀ Yoòbá ni kìí ṣe ojúlowó ọmọ Yoòbá. Ti wọn ò tiẹ̀ naani nípa ítàn àti àṣà..

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 2 месяца назад +2

    Àwọn Afaa àti àwọn Ekaladehan ni wọ́n nba ìtàn wa jẹ́.

  • @suadahitv1684
    @suadahitv1684 2 месяца назад

    Mansah allah ❤

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 2 месяца назад

    Islam koni Esin Abalaye oo
    Yawudi ati Nasora nko
    Annabi Muhammad S A W lomu Islam wa
    Itan tio ruju ni

  • @tosinogidiolu1
    @tosinogidiolu1 2 месяца назад +3

    Thank You, Aare Laji

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 2 месяца назад

    Irenimogun na ni Alhaji Kollington Ayinla.. "Akọlawọlé o, a tún dé oo. Irenimogun o. a tún de oo... Ẹ dákun ẹ gbà o. sànmọ̀ri, ó yá ká jọ jó Kollington,, oyinmọmọ..". (orin Kollington)

  • @AjoseMoshoodokemati
    @AjoseMoshoodokemati 2 месяца назад +4

    isokiso awon alfa tipoju si Ile Yoruba, ti o obasese ki ada eko Kiko ni ilana islamm duro ni awon Ile eko ni ile yoruba. (ni iwoye temi) eku ishe sir.

  • @sangodipetope3683
    @sangodipetope3683 2 месяца назад

    Ọpọlọ yin ko ni jọ́bà lasẹ Èdùmàrè. Baba you are trying on Yoruba History to the core.

  • @AdelekeRidwan-g3i
    @AdelekeRidwan-g3i 2 месяца назад +2

    ❤️❤️❤️

  • @adesinaisaactaiwo1065
    @adesinaisaactaiwo1065 2 месяца назад +1

    Sir please you will do well sir if you extend your invitation to prof wole soyinka

  • @MikhailAwolowo-zm7fr
    @MikhailAwolowo-zm7fr 2 месяца назад +1

    Social media ti wa expose opolopo awon alfa wa wipe won poor in knowledge, won si ya ole lati se research. Eleyi fihan wipe won ko ni le pass proper and well grounded knowledge si awon omo kewu ati janmo won. Awon student won a wa gba knowledge ti o ma fa idojuti fun won ti won ba wa ni awujo awon eleko ti o to gbangba sun l'oye.

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 2 месяца назад

    Koto di wipe
    Awon Alfa Alakatakiti de
    Sebi Awon Baba wa kan loko itan kale

  • @lateefbello5127
    @lateefbello5127 2 месяца назад

    Factual…

  • @afolabiowolabi5456
    @afolabiowolabi5456 2 месяца назад

    E ku ise takuntakun

  • @AdejumoSunday-sl8zo
    @AdejumoSunday-sl8zo 2 месяца назад +1

    Idi bebere ti ja ileke

  • @oluwaseunomotayoayeni821
    @oluwaseunomotayoayeni821 2 месяца назад +1

    Omoale eyan lon fi owo osi juwe Ile baba re, walahi omo ale ni were Alfa yi,, infact not him alone 90 percent alfa in Yoruba land they are bastard, rest well shelk ADAM alelori

  • @hammedadekunle9826
    @hammedadekunle9826 2 месяца назад

    Now they said when they bring Islam come they are worshipping idol how someone we come out and tell us history Islam senior yoruba and Yoruba traditional religion

  • @adeniyitemilola2560
    @adeniyitemilola2560 2 месяца назад

    We need to stop Islamic school's in yoruba land because most of their teachers and students are cause too much problem in yoruba land

  • @janetjanet3782
    @janetjanet3782 2 месяца назад

    Please does ede start with traditional crown I mean ancients crown ?? Does Ede town started with ancient crown ? And I heard Ede was founded about over 1,500 years ago durning the reign of alafin Sango 3rd alafin of oyo how true is this please enlight me

    • @abeebwahab6517
      @abeebwahab6517 2 месяца назад +1

      Not alaafin sango era,
      They didn't start with ancient crown they start with baale, because he's immigration officer there likewise laderin of illorin then. They start with baale

  • @kehindejosephkashimawo9410
    @kehindejosephkashimawo9410 2 месяца назад

    Ṣé ẹ rí àwọn Afaa tiwọn nba ìtàn jẹ́ yẹn, àwọn gan wọn ò mọ nípa ẹṣin Islam tí wọ́n jẹ Afaa lé lórí ni.. Ti wọ́n bá mọ nípa ìgbàgbọ́ nínú ẹ̀sìn Islam àti bí Islam ṣe jẹ́ ẹṣin itọ́sọ́na sí ìwà rere, ìyẹn ni wọ́n ó gbájumọ́. Kí ṣe kí wọ́n wá máa tako ẹ̀sìn èlẹ̀sìn, tabi kí wọ́n maa ba ìtàn jẹ́ bí àwọn kan nínú wọn ṣe máa ńṣe lórí social media.. Ko dìgbà tí wọ́n bá ba ìtàn jẹ́ tàbí so alufanṣa nípa àwọn ẹṣin míì.. Oun tó yẹ ki wọn má ṣe ní láti má tọ́ àwọn Janmọ́ wọn sọ̀na lójú ona ti Ọlọ́hun.. Àti gbogbo àwọn nkan ti ẹ̀sìn Islam gbàgbọ́ ni rere àti dáadáa.. Kí wọ́n sì jẹ́ kí àwọn èèyàn máa rí àpẹẹrẹ ìwà dáadáa lára wọn. Eleyi ni yóò mú kí àwọn èèyàn gbà ẹ̀sìn Islam yẹn. Èmi kii se Musulumi o, tàbí elesin islam.. Èrò ọkàn tèmi nìyẹn..