C&S Hymn O Fun mi Ledidi

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 10 окт 2024
  • O fun mi l'edidi,
    Gbese nla ti mo je
    B'O ti fun mi,O si rerin
    Pe, ”Mase gbagbe mi!"
    2. O fun mi l'edidi,
    O San gbese nla naa
    B'O ti fun mi osi rerin
    Wipe, "Maa ranti mi"
    3. Ngo p'edidi naa mo
    Bi' gbese tile tan
    O nso Ife eniti o San
    Gbese nla naa fun mi
    4. Mo wo,mo si rerin,
    Mo tun wo, mo sokun,
    Eri Ife Re si mi ni,
    Ngo toju Re titi
    5. Ko tun s'edidi mo,
    Sugbon iranti ni!
    Pe gbogbo gbese nla mi ni
    Emmanueli san

Комментарии • 9