Eyin ofa ika lara mi, eyin ofa ika lara awon omo mi, ofa aye lara emi ati awon omo mi, e gbo oro Oluwa e ba ina jade, ofa ba ina jade lara emi ati awon omo mi loruko Jesu
Lati orun wa, Oluwa so ina sinu ara mi, lati orun wa, Oluwa so agbara ina sinu awon omo mi, so agbara lu wa lati oke wa, agbara ina sokale ni mi ati awon omo mi loruko Jesu
Olorun Ojiji, fi oore-ofe ati aanu ojiji wa mi ri ninu osu yi, ki n le kuro ninu asale ile ti mo wa, ki aanu fohun fun mi ki iranlowo owo nla wole to mi ati awon omo mi loruko Jesu
Mo ti wa sibi aanu, Olorun jowo fi aanu be aye mi wo, ran mi lowo Olorun, fi aanu fa owo mi soke, fa owo awon omo mi soke pelu aanu ati oore tuntun loruko Jesu
Amen Amen Amen
I connect my self and my family to the prayer alter Amen Amen Amen
Amen Amen Amen in Jesus name
Surely goodness and mercy shall follow me and I will dwell in the House of the Lord for ever and ever iJn (amen).
Baba mi oooo, so agbara sinu mi, so agbara sinu awon omo mi, agbara Olorun bo lu mi, bolu awon omo mi loruko Jesu
Olorun Odekunle Epaphras, dide fun iranlowo mi, gbe awon omo soke, ki won pade alaanu ati oloore to maa mu won de ibi giga loruko Jesu
The grace of the Lord Jesus Christ be with us now and forever more.
Hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah hallelujah
I received power...I ll between to see vision..in Jesus Christ name.
Thank you Jesus for your deliverance 🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏
Eyin ofa ika lara mi, eyin ofa ika lara awon omo mi, ofa aye lara emi ati awon omo mi, e gbo oro Oluwa e ba ina jade, ofa ba ina jade lara emi ati awon omo mi loruko Jesu
Baba mi ooo, gbe agbara sinu mi, Oluwa gbe agbara nla sinu awon omo mi loruko Jesu
Amen Amen Amen AMEN in Christ Jesus
Baba mi o gbe agbara sinu mi ati sinu awon omo mi ati idile won loruko Jesu.
Mo gba iserere mi pada, awon omo mi gba iyanu won pada loruko Jesu
Amin amin Jeeesu
Lati orun wa, Oluwa so ina sinu ara mi, lati orun wa, Oluwa so agbara ina sinu awon omo mi, so agbara lu wa lati oke wa, agbara ina sokale ni mi ati awon omo mi loruko Jesu
Amen , Amen and Amen ijmn
More grease to our father and Mummy in the lord .E o pe fun wa o Amin
❤❤❤❤❤❤
Olorun ojiji je ki owo re o kan mi loruko jesu 🙏
Oluwa jeki awon omo mi ati idile won pade alanu ti yo gbe won losi ibi giga, oluranlowo Atoke wa kowa awon omo mi ri loruko Jesu.
Amin Amin Amin ni oruko jesu krist
Olorun Odekunle Epaphra gbe iranlowo dide fun awon omo mi ati idile won, fi aanu yanju oro aye won loruko Jesu.
Mo nino iranlowo fun Olorun fun igbe dide mi lati kuro ni asale ti mo wa loruko Jesu
God have mercy on me
Amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen amen inJ.
Amen 🙏🏿🙏🏿
Amin oo
Amin jesu
Amen ijn
ori oke yi se alati lehin mi amin loriko Jesu Oluwa
Olorun Ojiji, fi oore-ofe ati aanu ojiji wa mi ri ninu osu yi, ki n le kuro ninu asale ile ti mo wa, ki aanu fohun fun mi ki iranlowo owo nla wole to mi ati awon omo mi loruko Jesu
Amen 🙏
Mo ti wa sibi aanu, Olorun jowo fi aanu be aye mi wo, ran mi lowo Olorun, fi aanu fa owo mi soke, fa owo awon omo mi soke pelu aanu ati oore tuntun loruko Jesu
Amen
Baba mi o , Eseun mi o.
🎉🎉🎉🎉🎉
I'm here
Sarah Azeez
Amin Amin Amin ni oruko jesu
Nitori awa aysnfe esokale ni ola ni oruko jesu
Baba mi ooooooooooooo
🎉🎉🎉🎉🎉🎉🎉🎉🎉
💃💃💃💃💃
Olore mi ema seun mi o .
Agbara ma darikan gbe wo mi tomotomo, agbara ti ko see kolu, agbara ti ko see rifin, agbara to ko see foju di, Oluwa gbe wo mi tomotomo
😊😊😊😊
Ori oke yi SE alati leyin mi
Olorun Ojiji fun mi ni alert ojiji to maa gbe mi kuro ninu asale tomotomo
Amen Amen Amen Amen Amen Amen Amen 🙏
Amen Amen Amen
BABA mi ninu ipade toni je ki owo re o kan mi loruko jesu 🙏
Baba mi ninu ipade Toni jeki emi abosede ri temi se ki owo re kan aye mi
Amen ijn
Amen
❤❤❤❤❤❤❤
💃💃💃💃💃💃
Amen Amen Amen
Amen
Amen
Amen
❤❤❤❤