IṢEJỌBA TINUBU: EYI LOHUN TO MAA ṢẸLẸ LATI ASIKO YII LỌ - BỌDE GEORGE

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 27 авг 2024

Комментарии • 37

  • @abayomi.amenolasupo2713
    @abayomi.amenolasupo2713 Месяц назад +4

    Baba Bode George e mo otito sugbon nitori ijekuje ti eyin Afenifere nje ni o je ki e le so otito bi eyin agbagba ile Yoruba se nfi iya je mekunnu atubotan yin ko ni dara ni ase Edumare.

  • @kolaomilabu3563
    @kolaomilabu3563 Месяц назад +5

    The problem of Nigeria is too much people were currupt .Especially the leaders.

    • @kolaomilabu3563
      @kolaomilabu3563 Месяц назад +4

      Many people were currupt ,The leadersOle ni GBOGBO yin.

  • @Babatope-up4iu
    @Babatope-up4iu Месяц назад +2

    Baba George may be part of the problems but he's saying the truth here.

  • @lanrea9373
    @lanrea9373 Месяц назад +12

    Eyin na pelu awon ti o ba ilu yi je Yoruba Nation ti duro emu enu kuro ninu restructuring ati koja iyen ni ibi ti ade yi.

  • @oloriyeyeoge
    @oloriyeyeoge Месяц назад +1

    AGBALAGBA IKA PATAKI,anu yin shey mi pupo😢

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi Месяц назад +7

    BABA ALABOSI NIYIN , ONIJEKUJE NI GBOGBO YIN OLEEE , E BERU ATUNBOTAN YIN LORI OMO EYIN AFENIFEBI , OLORUN OOO LATI 60YEARS AFENIFERE , NISE LOHUNBURUU SI .

  • @allstars6443
    @allstars6443 Месяц назад +2

    Go rest sir all we need is yoruba nation you are gradually bcome talkative

  • @user-hp5um9hs1b
    @user-hp5um9hs1b Месяц назад +2

    Mr Bode George ikan kan ni gbogbo yin ati president ati eyin na gbogbo yin ole ni gbogbo yin lotori president ati eyi afenifere ise wo ni gbogbo se ti e fi ni owo president ise wo ni o se ke to je president gbogbo yin le ba nigeria je jeki o kalulu lo ni proto ni tori president ati gbogbo ole ni gbogbo yin gbogbo owo eko ni o gba jo

  • @florencedairo3888
    @florencedairo3888 Месяц назад

    Daddy wa , Eku eto Olorun a jęki epe fun wa sir, moro pe ki apin ni ona a Ayo, ko si ona miran ,ti a gba Ominira , awon omo wa to wa ni idą le won awale ,awon awa sile lati wa da ise sile. Elę yi ti awon Fulani yi pa wa to. Yoruba nation no going back .

  • @quazeemabdullahi2774
    @quazeemabdullahi2774 Месяц назад +1

    Afiki olorun o bawa da orile Ede yi ru patapata kiobawa tunto amin

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 Месяц назад +1

    Eni nko orin.. Fela Anikulapo to fi bun eyin ika agbalagba yii .. Eyin e nko orin fale tiko bani bayin wi baba 🤓👈😜

  • @abassyahaya9660
    @abassyahaya9660 Месяц назад +6

    Baba yi lo wa ibi kan joko si, olori ole ni iwo na

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp Месяц назад +8

    OTITO TI SONU TIPE TIPE

  • @RolynRolyn
    @RolynRolyn Месяц назад +3

    Baba bode, You still dey Nigeria? Or you don run to Ghana as you said before.

  • @Ire...6838
    @Ire...6838 Месяц назад +1

    Hahaha... Baba won Bode George!!! E ma binu si oro timo feso yio, 🫣 eni itiju kobo sir... Sebi Olori niyin ninu ipo PDP tese , e pelu awon to fi iya jewa baba won, ipo yin ni ilu eko lo koba ise mi... Omokekere ara mi.. Mowa iranlowo wa si odo yii e lemi danu ni, eyin Olori buruku ojelu yii ti fi iya jewa omo talaka.... Aburo yii Tinubu naa de bee tan ohun naa tun fi iya jewa titi mo eyin naa... Ewa soro radarada jade lenu... Nkan ti seyi. Baba ole nla ni eyin naa 🤓👈😜

  • @emmanueloguntunde802
    @emmanueloguntunde802 Месяц назад

    Baba eyin niyen,Olorun niyen,oju Oluwa wo yin pelu ibi ti e ba gbogbo re de.

  • @kemoblunsky3794
    @kemoblunsky3794 Месяц назад +4

    Gbogbo yin te pe ara yin ni agbagba yoruba, ika ni yin, eke m ba eke soro, iro n pa iro fun ro, SMH, eyin nu, OLORUN nu.

  • @rasheedadeosun6233
    @rasheedadeosun6233 Месяц назад +3

    Tinubu wolu...!
    * Eemon wolu.....!

    • @oloriyeyeoge
      @oloriyeyeoge Месяц назад +1

      The man speaking is the number one eemo to enter the country!💔😱

  • @ruthlawal4260
    @ruthlawal4260 Месяц назад

    Only God can help us in nigeria,
    Ki Olorun se idajo lori gbogbo awon to ba nigeria je.

  • @abayomi.amenolasupo2713
    @abayomi.amenolasupo2713 Месяц назад +2

    Baba Bode George e je ki Yoruba ko da duro ede wa ko ye ara wa ki Yoruba da duro ki Hausa na da duro ki Yibo na da duro corruption ko le kuro ni Nigeria titi aye yo fi pare Awon Fulani so pe awon ni awon ni Nigeria Baba Bode George e pin wa ko to di pe e fi aye sile ki Yoruba le ma ranti yin si rere (From USA)

  • @abetoba2331
    @abetoba2331 Месяц назад

    Gbogbo isoro towa nita yi Ona abayo SI Isoro yi ni YORUBA NATION

  • @BamideleMathew-tg6pe
    @BamideleMathew-tg6pe Месяц назад +5

    Ole ni gbogbo yin both pdp, apc, labour and so on. Yoruba nation la fe.

  • @horlahinksj7644
    @horlahinksj7644 Месяц назад +1

    Bàbá, you never commot for Nigeria?

  • @truthsquestions1532
    @truthsquestions1532 Месяц назад

    ❤❤❤

  • @taiwowemimo1856
    @taiwowemimo1856 Месяц назад

    Capital N Ò no restructuring Yoruba Nation lafe no going back please

  • @johnsondjohnsonpga5948
    @johnsondjohnsonpga5948 Месяц назад +1

    Gbogboyin lema sare

  • @OrigbemisoyeOluwaJenyo
    @OrigbemisoyeOluwaJenyo Месяц назад +4

    Baba oloriburuku ni yni .won bere ominira ile yoruba nationa .ni to owo ti ewakiri .enbere atuto .lo odun woni e eyni baba oni jekuje tie mo ibi ti emaku si. Eyni agba osi radara

  • @mutiuadebayo1802
    @mutiuadebayo1802 Месяц назад

    Politicians all of them are the same

  • @akeemakande-hp4ot
    @akeemakande-hp4ot Месяц назад +1

    Baba emi oni buy-in Tori baba leje amo omale Ryan nifi owo OSI juwe ile baba re ,to ba se pe Peter obi omo Ibo te tileyin loba WOLE ni ENI man se radarada OSI ti enso yen baba alatenuje ofo ,se Toba je omo yin ni TINUBU se elema wa ki omo ni aseyori rere eyin ori use rere ti TINUBU se so ,se YORUBA naa ni eyin naa sa?egbe afenifere ti e se NBO lebaja ?baba agba Sonu

  • @taiwohenryolajide1262
    @taiwohenryolajide1262 Месяц назад +2

    Instead of him to support Yoruba Nation, he's there talking nonsense.

  • @emmanueloguntunde802
    @emmanueloguntunde802 Месяц назад +1

    Baba you are Completely confused,when you are above 70 years you will be having dementia disease,that’s why you are saying kantan kantan,eyin alabosi yi.

  • @oloriyeyeoge
    @oloriyeyeoge Месяц назад +3

    Th truth of the matter is,you ppl are interviewing thé most uncaring indecent of the whole lot of them! What you want to ask him is- why is he Not supporting,bt opposing his race (Yoruba nation)that is struggling for self determination to be able to fight off the Fulanis who are killing all our farmers so as to starve the west to death?
    If he can answer that query, then,we’ll be able to start to see where things went wrong
    🤷‍♀️💔😪🥲😭😱

  • @loantha2996
    @loantha2996 Месяц назад +1

    PDP, go and work with northern youths. Useless baba blah blah blah