E PADE OLUDANI NI MONRAN (ADURA 2)

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 16 окт 2024

Комментарии • 28

  • @wumiodubiyi7262
    @wumiodubiyi7262 18 дней назад

    E seun pupo olootu fun imoran yi lakaye yin koni pare lase olohun ❤❤❤❤❤

  • @AwokoyaAnikeabosede
    @AwokoyaAnikeabosede 20 дней назад +1

    ❤❤❤

  • @monsuruakinkunmi2386
    @monsuruakinkunmi2386 15 дней назад

    Eseun olugbani imoran . Ko si ohun titun labe orun. Imoran temi ni pe ki won fe Ara won. Tori pe kehinde yi ti mo owo re bakanna awon omo yi ti mon daada,

  • @alimatonashokun8497
    @alimatonashokun8497 20 дней назад

    Ese Olotu ni imoran temi ki ofe ikeji iyawo e nitoripe oku ni esin faramo be ese.

  • @sarahyusuf4201
    @sarahyusuf4201 20 дней назад

    Hummm may Allah guide us ♥️ 🙏🏾

  • @MOUSSAWaheed-cx6qs
    @MOUSSAWaheed-cx6qs 19 дней назад

    Ekuse olootu eto olorun aranwalowo
    Ti kobafe omobirin yen,Aaaa,nkan ase omobirin yen ooo,toripe omobirin yen gan oti nifere pupo,kofe pelu nini emi imoore ,ati ijeran I've toun naa nisi omobirin yen.
    Eleekeji nipe oro ibeji soro,boya kadara won nipe Oko kan naa lomaafe won.
    Ki omokunrin yen kofe ikeji iyawore koma fi owo arae da inule e ru, ati igbesi aye arare.
    Esee pupo.

  • @ElizabethOye2212
    @ElizabethOye2212 20 дней назад

    God bless you sir

  • @wumiodubiyi7262
    @wumiodubiyi7262 18 дней назад

    Imoran temi nipe ki Arakunrin yen ko fe ikeji iyawo e ooo ko ma fe obirin kankan lati ita oooo ikeji iyawo e ni kofe to ba fe ni ifokanbale ninu igbeyawo e ooo e seun pupo oludani ni imoran lakaye yin koni pare lase olohun

  • @wumiodubiyi7262
    @wumiodubiyi7262 18 дней назад

    Hummm Ododo oro imoran agba e seun pupo olusotan wa lakaye yin koni pare lase olohun

  • @youssoufyoussouf5894
    @youssoufyoussouf5894 20 дней назад

    Bonsoir que dieu vous protège a tous danger

  • @jamiuabayomi7957
    @jamiuabayomi7957 20 дней назад

    It is right Islamically

  • @momohabdulrasheed8889
    @momohabdulrasheed8889 19 дней назад +1

    He should go ahead and marry her, it has been destined by God that they will be together and only God know how He arranged it that way. Thank you sir.

  • @ajokeakeem5834
    @ajokeakeem5834 17 дней назад

    Eseun oludani nimoran wa,adua tiyi na agba o

  • @SafeSeniors5
    @SafeSeniors5 19 дней назад

    Ese olotu Olorun a ma fun yin se ki o fe ko si laifi bi olorun ti fe ni

  • @OluwamayowaFagbenja
    @OluwamayowaFagbenja 20 дней назад

    Okunrin yee lefe ekeji iyawo re, because iyawo re kose ni ayie mo olefee eni tiowu lati okan ree. Thanks

  • @davidakenbi780
    @davidakenbi780 20 дней назад

    Ni time emio kosi inkan ti kosele ri labe orun ko ya tete fe ekeji iyawo re ki elomiran to fe nitoripe akosile ti wa pe omafe nikoje ki ekeji iyawo re ri oko fe ,olorun ti ri opin ati ibere gbogbo inkan,AKOSILE KI YIO YE,

  • @ganiyusalawu749
    @ganiyusalawu749 19 дней назад

    Toba jẹ ti esin islaam ni kosi ohun ti o tako,ki awọn mejeeji wa l'aiye ni Olohun o fẹ toba jẹ ti islaam ni o to daada

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 12 дней назад

    Eni ti olohun koma tele na niyen
    Aimo Kadara lo gbe won Rin irin Ajo akoko
    Kosi aburu nibe ninu Esin mi ati Asa mi

  • @MufaidatatAbdulsalam
    @MufaidatatAbdulsalam 12 дней назад

    Eku eto.mioniwayiti.kotiburu kiwanfe ekeji iywowan iyeturorun fuwanke

  • @ElizabethOye2212
    @ElizabethOye2212 20 дней назад

    Hmmmm, I could said he should marry the twins sister, esu ta ti mo yato si angeli tun tun. Because if he marry another outsider she can destroy what he’s already build

  • @opeyemi3258
    @opeyemi3258 19 дней назад

    Kolofe

  • @abdallahfrancisco3347
    @abdallahfrancisco3347 19 дней назад

    Bonjour olotu ou Isè oloré olorun à ranwalowò
    Il n'a qu'à épouse la jumelles de sa femme pusque elle connaît bien sa comportement et elle aussi connaît pour lui aussi
    Premièrement il n'a qu'à aller voir les parents de sa femme et tout exprique sûrement ils vont accepter
    Puisque la fille la aussi aime le messieur peut être elle a peut de le dire

  • @IbraheemIsmaheelalabi
    @IbraheemIsmaheelalabi 20 дней назад

    Ekaro sir ekú iṣẹ ọpọlọ, ọpọlọ náà kò ní jọba, ní ìmọràn titemi tí ẹsìn lslam náà faramọ ìgbà ti èkejì rẹ kó sí láyé máa olè fẹ ìbejì ìyàwó rè, kí ọlọhun ko fún wà nì agbọye ẹsìn rẹ

  • @ibouraimasoule8422
    @ibouraimasoule8422 20 дней назад

    il faut lui dire de marier la seconde de sa femme car c'est mieu pour lui que d'aller chercher une étrangère pour entretenir ses enfants.Pour finir rien n'est étrange dans cette vie

  • @youssoufyoussouf5894
    @youssoufyoussouf5894 20 дней назад

    Il a deux condition il peut marié et il n aura pas de problème mais il peut avoir de sérieux problème donc qu'il n'a qu'à demander la vie de femme d abord et la vie des parents

  • @margaretlewis4833
    @margaretlewis4833 20 дней назад

    Good morning moderator,there is nothing Dat happened now Dat has not been bf ,God has destined kehinde to be his wife so the two of them should set the balls rolling and inform their parents because marring another woman will not be as the sister so they should marry themselves

  • @BilikisuBolanle
    @BilikisuBolanle 15 дней назад

    He should go ahead and marry his wife twins sister in other to take good care of the children.

  • @ChitouSouberou
    @ChitouSouberou 18 дней назад

    Bonsoir forum de pronom media je demanderai de marier la sœur de sa femme