Hymn 621 - "Maleka Mimo T'Orun" - 46th Adult Harvest 2022

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 11 окт 2024

Комментарии • 7

  • @ury_bht9369
    @ury_bht9369 7 месяцев назад +2

    Maleka Mimọ t’Ọrun, Nwọn ti t’Ọrun sọkalẹ, Lati wa sure fun wa, Ninu Ijọ Mimọ.
    2: Ẹnyin ọmọ Ijọ Mimọ, Mura lati ṣe ifẹ Rẹ, Nitori o mbọ kankan, Lati bẹ wa wo.
    3: Gbogbo ẹnyin olupọnju, Ẹ kọrin kẹ ho f’ayọ,
    Nitori Oluwa mbọ,
    Yio da yin nide.
    4: Ayọ wa yio ti pọ to, Nikẹhin ni Ijọba Ọrun, Bi awa ba le mura, S’iṣẹ Oluwa.
    5: Ẹnyin oṣiṣẹ Oluwa,
    Mura lati siṣẹ na,
    Nitori ere nyin pọ,
    Li oke Ọrun.

  • @bamideleadegbuyi5431
    @bamideleadegbuyi5431 Год назад +2

    By God's grace I'll attend service here one day 🙏

  • @olorunmbeabraham
    @olorunmbeabraham Год назад +1

    Halleluya my church

  • @niyijohn8366
    @niyijohn8366 Год назад +1

    😘

  • @olujuwono.idowu-davies3830
    @olujuwono.idowu-davies3830 Год назад

    Please where is this parish located ?