- Видео 1 498
- Просмотров 3 207 194
ÀṢÀKẸ́ TV SHOW
Добавлен 23 дек 2021
ORÍ ÌKÀNNÌ YÌÍ WÀ FÚN KÍKÓ ÀTI KÍKÀ ÈDÈ YORÙBÁ PẸ̀LÚ ÌRÒYÌN BÓ ṢE Ń LỌ LỌ́WỌ́ LỌ́WỌ́
ÌYÁ ÌGBOHO ÀWỌN AKÍKANJÚ OBÌNRIN YORÙBÁ NATION.. 16/11 /2024
#yoruba #yorubanation #news #igboho #yorubanationnow #humanity #humanrights #yorubabrazil #nigeria #africa #law #love#land #wow#women #respect #response #wealth #justice #selfdetermination #security #one
Просмотров: 679
Видео
NÀÌJÍRÍÀ NÍLÒ $10bn LÁTI PÈSÈ INÁ MỌ̀NÀMỌ́NÁ TÍ KÒ NÍ ṢẸ́JÚ/ÀÌSÀN ÌTỌ̀ SUGA Ń BURÚ SÍ NÍ NÀÌJÍRÍÀ
Просмотров 2597 часов назад
#yoruba #nigeria #yorubanation #igboho #humanity #humanrights #yorubanationnow #yorubabrazil #news #africa
YORÙBÁ NATION NÌKAN ṢOṢO LỌ̀NÀ ÀBÁYỌ ELÉDÙMARÈ Á MÚ WA DÉ ILẸ̀ ÌLÉRÍ NÁÀ ÀMÍN ÀṢẸ ÈDÙMÀRÈ 🙏
Просмотров 1,3 тыс.9 часов назад
#yoruba #yorubanation #news #igboho #yorubanationnow #humanity #humanrights #yorubabrazil #nigeria #africa #selfdetermination #security #wealth #law #love#land #wow #women #work
BÀBÁ WA Ọ̀JỌ̀GBỌ́N BANJI AKÍNTÓYÈ BÁ GBOGBO ỌMỌ YORÙBÁ SỌ̀RỌ̀ Ẹ MÁ BẸRU Ẹ..
Просмотров 3,2 тыс.23 часа назад
#yoruba #yorubanation #news #igboho #humanity #yorubanationnow #humanrights #yorubabrazil #nigeria #africa #law #love #land #endnigerianow #endbadgovernance #respect #response #right #selfdetermination #uk #unitednations #trump #trending #asaketvshow #koiki
KÉÉÉÉÉÉÉÉÉRE ÒÒÒ!!! KÌÍ ṢE ÈMI NI OO.. 15 /11 /2024
Просмотров 6 тыс.2 часа назад
#igboho #news #nigeria #yorubanation #africa #humanrights
HÁÀ! KÀYÉFÌ ŃLÁ RÈÉ ÒÒ!! .. ÈMI NI MO JẸ ẸRAN ARA MÍ, Ẹ MÁ SỌ LOKO Ó.. 15 /11/ 2024
Просмотров 11 тыс.2 часа назад
#nigeria #yoruba #yorubanation #nigeria #africa #igboho #humanity #yorubanationnow #humanrights #news #yorubabrazil #oyostate #why
Ẹ WO ARA TI ÀWỌN FULANI Ń FI OWÓ DÁ NÍLÉ YORÙBÁ.. 14 /11 /2024
Просмотров 4,1 тыс.4 часа назад
#news #yoruba #nigeria #africa #igboho #fulani #freedom #africanleaders #wealth #law#love #yorubanation #yorubanationnow #yorubanimi #igboho #yorubabrazil #nigeria#africa #response #right #rebel #justice
ÀṢÍRÍ BISHOP ILÉ ÌJỌSÌN UK TÓ JẸ́ T€RR0R¡ST TÍ BUHARI Ń LÓ TI TÚ Ò.. ÌJỌBA UK TI PÀṢẸ.. 14 /11 2024
Просмотров 13 тыс.4 часа назад
#yoruba #yorubanation #igboho #humanrights #news
OGUN DÉ Ò! GBÈSÈ RÈÉ Ò! ÀWỌN CHINA TI KÓGUN WỌ̀LÚ, ÌJỌBA NÀÌJÍRÍÀ TI PADÀ.. 13 /11 /2024
Просмотров 4,2 тыс.4 часа назад
#news #nigeria #yoruba #yorubanation #africa #igboho #humanrights
ÌGBOHO ÒÒṢÀ LATEST UPDATE GBOGBO ( FILE ) WỌN RÈÉ LỌ́WỌ́ MÍ ÀṢÍRÍ..
Просмотров 5 тыс.7 часов назад
#igboho #yorubabrazil #oyostate #news #nigeria #yoruba #yorubanation #yorubanationnow #yorubanimi #igboho#yorubabrazil #freedom #africanleaders #wealth #law #love#land #wow #selfdetermination #endnigerianow #explore #secret
ÒṢÌṢẸ́ TI KÒ BÁ NÍ NỌ́MBÀ IGBELU KÒ NÍ GBA OWO OṢÙ RẸ̀ /TINUBU PÈ FÚN IDÀDÚRÓ OGUN NÍ GAZA..
Просмотров 1,6 тыс.7 часов назад
#news #yoruba #nigeria #africa #yorubanation #humanity #saudiarabia #arabic
OONI ILÉ IFẸ̀ LỌ ṢE IDUPE NÍLÉ ÌJỌSÌN PẸLU ỌMỌ RẸ TADENIKAWO
Просмотров 4,3 тыс.7 часов назад
#ooniofife #yoruba #news #yorubanation #humanity #church
Ọ̀JỌ̀GBỌ́N BANJI AKINTOYE SỌ̀RỌ̀ LORI KINI O WA NÍNÚ ÌWÉ TI AGBE LỌ SÍ 10 DOWNING STREET Ọ̀RỌ̀ RẸ Ó.
Просмотров 6 тыс.9 часов назад
#yoruba #yorubanation #nigeria #igboho #humanity #yorubanationnow #news #yorubabrazil #humanrights #africa #love #respect #response #selfdetermination #security #separation #endbadgovernance #endnigerianow #education #freedom #peace#wemove
ILẸ̀ WA, ÌLÚ WA YORÙBÁ NATION Ó DÁRA Ó RẸWÀ..
Просмотров 7749 часов назад
ILẸ̀ WA, ÌLÚ WA YORÙBÁ NATION Ó DÁRA Ó RẸWÀ..
ÀWỌN ÀGBÀÀGBÀ FULANI NÍ KÍ WỌ́N LỌ MÚ ÌGBOHO ÒÒṢÀ.. 11/11 /2024
Просмотров 8 тыс.9 часов назад
ÀWỌN ÀGBÀÀGBÀ FULANI NÍ KÍ WỌ́N LỌ MÚ ÌGBOHO ÒÒṢÀ.. 11/11 /2024
KÍLÓDÉ TÍ ILÉ AYÉ DÌ ÒGÚN! GRANDPA BÁ ỌMỌ ỌMỌ RẸ̀ SÙN, ALHAJI ORIYOMI HAMZAT.. 10/11/2024
Просмотров 91312 часов назад
KÍLÓDÉ TÍ ILÉ AYÉ DÌ ÒGÚN! GRANDPA BÁ ỌMỌ ỌMỌ RẸ̀ SÙN, ALHAJI ORIYOMI HAMZAT.. 10/11/2024
Ó DOJÚ Ẹ Ò! ÀWỌN AGBE SUN INÚ OKO LÁTI DÁ ÀBÒ BO NKAN Ọ̀GBÌN WỌN.. 11 /11 /2024
Просмотров 94912 часов назад
Ó DOJÚ Ẹ Ò! ÀWỌN AGBE SUN INÚ OKO LÁTI DÁ ÀBÒ BO NKAN Ọ̀GBÌN WỌN.. 11 /11 /2024
Ó TI ṢẸLẸ̀! ÀṢÍRÍ ÀWỌN ỌBA TÓ TỌWỌ́ BOWE TI TÚ! OGUN MÁ JÀ ÒÒ.. 10 /11 /2024
Просмотров 7 тыс.12 часов назад
Ó TI ṢẸLẸ̀! ÀṢÍRÍ ÀWỌN ỌBA TÓ TỌWỌ́ BOWE TI TÚ! OGUN MÁ JÀ ÒÒ.. 10 /11 /2024
A kú ORÍ IRE Ò! GBOGBO ỌMỌ YORÙBÁ OWO BÁ INFORMAT ÀWỌN BOKO HAR@M Ó!
Просмотров 6 тыс.14 часов назад
A kú ORÍ IRE Ò! GBOGBO ỌMỌ YORÙBÁ OWO BÁ INFORMAT ÀWỌN BOKO HAR@M Ó!
ÌBẸ̀RÙ BOJO TI Ń GBỌKÁN ÀWỌN ÀLEJÒ TÓ Ń GBÉ AMẸ́RÍKÀ.. 10/11 /2024
Просмотров 2,5 тыс.14 часов назад
ÌBẸ̀RÙ BOJO TI Ń GBỌKÁN ÀWỌN ÀLEJÒ TÓ Ń GBÉ AMẸ́RÍKÀ.. 10/11 /2024
HÁÀ! ÀṢÍRÍ ILÉ ÌJỌSÌN BÌRÌTÌKÓ ÀWỌN TÓ KÓ WA LẸ́RÚ TI TÚ Ò .. 9/11 /2024
Просмотров 5 тыс.16 часов назад
HÁÀ! ÀṢÍRÍ ILÉ ÌJỌSÌN BÌRÌTÌKÓ ÀWỌN TÓ KÓ WA LẸ́RÚ TI TÚ Ò .. 9/11 /2024
Ọ̀PỌ̀ ÈNÌYÀN LÓ TÚN TI WÀ NÍNÚ ÒKÙNKÙN BIRIMÙ BÁYÌÍ, LẸ́YÌN TÍ INÁ MỌ̀NÀMỌ́NÁ NÀÌJÍRÍÀ JÁ LULẸ̀..
Просмотров 49616 часов назад
Ọ̀PỌ̀ ÈNÌYÀN LÓ TÚN TI WÀ NÍNÚ ÒKÙNKÙN BIRIMÙ BÁYÌÍ, LẸ́YÌN TÍ INÁ MỌ̀NÀMỌ́NÁ NÀÌJÍRÍÀ JÁ LULẸ̀..
ÀṢÍRÍ ÌJỌBA BÌRÌTÌKÓ TI TÚ ÒÒ! LÓRÍ Ọ̀RỌ̀ 2075..8/11 /2024
Просмотров 7 тыс.19 часов назад
ÀṢÍRÍ ÌJỌBA BÌRÌTÌKÓ TI TÚ ÒÒ! LÓRÍ Ọ̀RỌ̀ 2075..8/11 /2024
BÀBÁ KOLA OLOOTU TI PADÀ TẸ́ O! ÀWỌN IRÚNMỌLẸ̀.. 8/7/2024
Просмотров 78219 часов назад
BÀBÁ KOLA OLOOTU TI PADÀ TẸ́ O! ÀWỌN IRÚNMỌLẸ̀.. 8/7/2024
KÀYÉFÌ NLA RÈÉ OO! OHUN TÍ KÒ ṢẸLẸ̀ RÍ TI Ń ṢẸLẸ̀ OO! Ó DOJÚ Ẹ 7/11 /2024
Просмотров 2,6 тыс.21 час назад
KÀYÉFÌ NLA RÈÉ OO! OHUN TÍ KÒ ṢẸLẸ̀ RÍ TI Ń ṢẸLẸ̀ OO! Ó DOJÚ Ẹ 7/11 /2024
Ó Ń RÚGBÓ Ń BỌ̀! Ẹ FÚNRA! ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ TUNTUN MÌÍRÀN TÍ Ó Ń JẸ́ "LAKURAWAS"TI WỌ ILẸ̀ NÀÌJÍRÍÀ
Просмотров 1,7 тыс.21 час назад
Ó Ń RÚGBÓ Ń BỌ̀! Ẹ FÚNRA! ÀWỌN AGBÉSÙNMỌ̀MÍ TUNTUN MÌÍRÀN TÍ Ó Ń JẸ́ "LAKURAWAS"TI WỌ ILẸ̀ NÀÌJÍRÍÀ
STRONG MESSAGE FROM PRO BANJI AKINTOYE TO ALL OBAS
Просмотров 9 тыс.День назад
STRONG MESSAGE FROM PRO BANJI AKINTOYE TO ALL OBAS
ÀWỌN ABIYAMỌ AYÉ TÍ BÍNÚ TÁN.. 5/11 /2024
Просмотров 5 тыс.День назад
ÀWỌN ABIYAMỌ AYÉ TÍ BÍNÚ TÁN.. 5/11 /2024
Ó TI ṢẸLẸ̀! ÈDÈ ÀÌYEDÈ TÍ BẸ́ SÍLÈ LÁÀÁRÍN ÀWỌN GOMINA ILẸ̀ YORÙBÁ 5/11 /2024
Просмотров 3 тыс.День назад
Ó TI ṢẸLẸ̀! ÈDÈ ÀÌYEDÈ TÍ BẸ́ SÍLÈ LÁÀÁRÍN ÀWỌN GOMINA ILẸ̀ YORÙBÁ 5/11 /2024
ÀMÍN ÀṢẸ ÈDÙMÀRÈ.
Àmín, Àṣẹ. E ku isẹ ìlú. Ayunlo, àyúnbọ̀ ni ọwọ ny'enu. È e lo l'ayọ, è e bo l'ayọ, ìkọ kìí ko ejo lẹsẹ. Ọkọ yin ko ni fi orí sọ igi, ọnà ko ni di ìgbé mọ awakọ̀ yín lọwọ o. A nwo yín láti òkè òkun. Inú wa ndùn si yi. Gbogbo ádùrá yín a gbà l'oruko Jésù. E ku isẹ takuntakun.❤❤❤❤
Amin betiwi lomari aro aromo yoruna nation no going back
Orile Yoruba ni Kia Kia.Amin
Ase aseyi, samodun,seemii Oju o ni ti awa yoruba atata 👍❤
Amin jesu,mo gba fun yin jare.yoruba nation now
Yoruba nation no going back
YORUBA NATION NO GOING BACK BY THE SPECIAL GRACE OF GOD ALMIGHTY. IGBOHOOOOOO!!!!!OOSA OWO BABA DAMMY OMO ALADINKUN EKUN OKO FULANI KO NII SUU YIN KO NI RE YIN LASE ALAWURA
Eku ise ilu o Ile ominira Yoruba NATION tiwa ntiwa ma DURO. Ni bi ti ko ni si IJE KU JE OSELU.
Amin Amin Amin Ase Ase ni tedumare, Yoruba nation lafe ni kiakia laipe no going back.
E jowo e ba wa awon jagunjagun ile Yoruba ki won dide ati kun Sunday Igboho Osaa lowo lati gba ile yoruba fun wa. E ku ise takuntakun, eyin baba, iya ati egbon wa
She has dementia
Yoruba Nation no going back. Watching from UK
AMIN ASEE
Amin Asee Edumare
AMIN AMIN AMIN. Be loma ri. Oluwa awa so yin lo, aso yin bo layo ati alafia.
Asee asee asee❤❤❤❤❤❤❤
Aseeeee wa
Eku ise takuntakun
🇺🇿🇺🇿🇺🇿✊✊✊💪💪💪👍👍👍❤️❤️❤️🙏🙏🙏💯💯💯
Ase Orun gun koribee
Ase gun 🙏🙏🙏
Amin Jesu ❤❤❤
Alo ire òò ẹ gunle layo lagbara Eledumare
Ele yii tun lee
Amin Jesu
Aseeeee
Eku ise ilu eku ise takuntakun Elédùmarè a ràn wá lọ́wọ́
Yoruba nation no going back
Iya yi to ge No going back
Yoruba nation mouvement of the people of Yoruba land
Yoruba nation no going back
Asake you are well done ✅ Yoruba nation will come to reality by the grace of God
Orile ede Yoruba nikan lona abayo epin ilu yii se
Amin asee Edumare 🙏
Yoruba nation no going back
Layo layo o Amin asee Edumare 🙏 asee oo
Save journey oo
Asee wa
Weldone people,
Ominira se pataki
Yoruba nation now
Inkankan ko ni sele siiyin o
Floored e bale layo
Aseeeeeee ooooooooo
❤Ni Oruko Olorun gbogbo won ni Aseri won ma tun, won po be ti won pa awon omo olomo. Aseri won seven Bere si tun ni, aseri o ni bo.
Yoruba nation no going back
Ase nt'Edumare
Aseeeee
Yoruba nation no going back