Etioba TV
Etioba TV
  • Видео 243
  • Просмотров 207 195

Видео

ẸNI TI NURUDEEN ALOWONLE TORII RẸ DERO AGỌ ỌLỌPAA TI SỌRỌ O
Просмотров 782 часа назад
ẸNI TI NURUDEEN ALOWONLE TORII RẸ DERO AGỌ ỌLỌPAA TI SỌRỌ O
GOMINA ADELEKE, WAHALA TUNTUN TI N RUGBO BỌ LAARIN ILOBU ATI IFỌN O
Просмотров 1164 часа назад
GOMINA ADELEKE, WAHALA TUNTUN TI N RUGBO BỌ LAARIN ILOBU ATI IFỌN O
Awọn ọlọmọọba fẹhonu han l'Oṣogbo, wọn ni Ataọja ti dori aṣa awọn kodo
Просмотров 564 часа назад
Awọn ọlọmọọba fẹhonu han l'Oṣogbo, wọn ni Ataọja ti dori aṣa awọn kodo
Ijọba, ẹ gba mi, Ataọja ti yan mi jẹ o - Olori Adenle ke gbajare
Просмотров 154 часа назад
Ijọba, ẹ gba mi, Ataọja ti yan mi jẹ o - Olori Adenle ke gbajare
Ọlọpaa lo fun mi ni ibọn ati ọta tawọn ọlọpaa ba ninu mọto mi - Alowonle, ọga onimọto l'Ọṣun jẹwọ
Просмотров 317 часов назад
Ọlọpaa lo fun mi ni ibọn ati ọta tawọn ọlọpaa ba ninu mọto mi - Alowonle, ọga onimọto l'Ọṣun jẹwọ
Awọn mọlẹbi Ọgagun Taoreed Lagbaja to doloogbe barajẹ gidigidi
Просмотров 76114 дней назад
Awọn mọlẹbi Ọgagun Taoreed Lagbaja to doloogbe barajẹ gidigidi
Njẹ ẹ ti gbọ? Oṣere tiata ilẹ wa nni, Agbako, ti ku o
Просмотров 1521 день назад
Njẹ ẹ ti gbọ? Oṣere tiata ilẹ wa nni, Agbako, ti ku o
Awọn afọbajẹ ti yan Olumoro ti ilu Moro o
Просмотров 89121 день назад
Awọn afọbajẹ ti yan Olumoro ti ilu Moro o
Oṣogbo: Awọn agbẹ figbe bọnu, wọn ni ijọba ti fi katakata hu gbogbo ere-oko awọn danu
Просмотров 25521 день назад
Oṣogbo: Awọn agbẹ figbe bọnu, wọn ni ijọba ti fi katakata hu gbogbo ere-oko awọn danu
AFARA ỌLAIYA: Ẹgbẹ wa ko nii fọwọ lẹran ki PDP ba ipinlẹ Ọṣun jẹ - BANIK
Просмотров 21128 дней назад
AFARA ỌLAIYA: Ẹgbẹ wa ko nii fọwọ lẹran ki PDP ba ipinlẹ Ọṣun jẹ - BANIK
ỌLADAPỌ RA MỌTO OLE, O TUN LỌỌ GBEGBA ỌPẸ NI ṢỌỌṢI
Просмотров 622 месяца назад
ỌLADAPỌ RA MỌTO OLE, O TUN LỌỌ GBEGBA ỌPẸ NI ṢỌỌṢI
ỌBA ADEDAPỌ ADERẸMI, OLOJUDO TI IDO-ỌṢUN, O DI GBERE O
Просмотров 3172 месяца назад
ỌBA ADEDAPỌ ADERẸMI, OLOJUDO TI IDO-ỌṢUN, O DI GBERE O
Idi ti mo fi ba akẹkọọ OAU lo pọ ninu igbo - Ọlọkada jẹwọ
Просмотров 973 месяца назад
Idi ti mo fi ba akẹkọọ OAU lo pọ ninu igbo - Ọlọkada jẹwọ
Lẹyin ọdun mejila to ti n rugba Ọṣun, Ọṣuntomilọla ti re'le ọkọ o
Просмотров 833 месяца назад
Lẹyin ọdun mejila to ti n rugba Ọṣun, Ọṣuntomilọla ti re'le ọkọ o
Emi ni mo maa n di awọn obinrin ti ọkọ mi maa n pa sinu ile wa lẹsẹ mu - Mariam
Просмотров 883 месяца назад
Emi ni mo maa n di awọn obinrin ti ọkọ mi maa n pa sinu ile wa lẹsẹ mu - Mariam
Orukọ awọn Ataọja to ti jẹ niluu Oṣogbo
Просмотров 313 месяца назад
Orukọ awọn Ataọja to ti jẹ niluu Oṣogbo
Ajọdun ẹgbẹ Emere Onitẹsiwaju
Просмотров 1223 месяца назад
Ajọdun ẹgbẹ Emere Onitẹsiwaju
Awọn ọmọ ẹgbẹ Emere onitẹsiwaju ṣajọdun l'Ọṣun
Просмотров 4883 месяца назад
Awọn ọmọ ẹgbẹ Emere onitẹsiwaju ṣajọdun l'Ọṣun
Ibọrisa ki i ṣe aṣa wa nilẹ Yoruba - Oluwoo ti ilu Iwo
Просмотров 473 месяца назад
Ibọrisa ki i ṣe aṣa wa nilẹ Yoruba - Oluwoo ti ilu Iwo
Tinubu, awọn ọkọ wa ti sa lọ nitori wahala eto ọrọ-aje yii o
Просмотров 973 месяца назад
Tinubu, awọn ọkọ wa ti sa lọ nitori wahala eto ọrọ-aje yii o
Ijọba Tinubu n Fi Ara ni Awa Akanda Ẹda
Просмотров 433 месяца назад
Ijọba Tinubu n Fi Ara ni Awa Akanda Ẹda
TINUBU, Ẹ ṢAANU WA, NNKAN LE O
Просмотров 483 месяца назад
TINUBU, Ẹ ṢAANU WA, NNKAN LE O
Imọran Ree Fawọn Olufẹhonu han atijọba
Просмотров 613 месяца назад
Imọran Ree Fawọn Olufẹhonu han atijọba
AYAN AGALU
Просмотров 143 месяца назад
AYAN AGALU
Awọn ọmọ Yahoo ni mo fẹẹ fi gogongo ọrẹ mi ti mo yọ gun ọṣẹ fun - Ganiyu jẹwọ
Просмотров 5803 месяца назад
Awọn ọmọ Yahoo ni mo fẹẹ fi gogongo ọrẹ mi ti mo yọ gun ọṣẹ fun - Ganiyu jẹwọ
L'Ọṣun, Ọpẹyẹmi jẹwọ ibi to ti ri ẹran eeyan ti wọn ka mọ ọn lọwọ
Просмотров 1,1 тыс.4 месяца назад
L'Ọṣun, Ọpẹyẹmi jẹwọ ibi to ti ri ẹran eeyan ti wọn ka mọ ọn lọwọ
Emi ni mo pa Sikiru Ọmọ Alhaja n'Ileṣa - David
Просмотров 19 тыс.4 месяца назад
Emi ni mo pa Sikiru Ọmọ Alhaja n'Ileṣa - David
Bọde Itapa, ogbologbo tọọgi tawọn ọlọpaa Ọṣun n wa ree o
Просмотров 9 тыс.4 месяца назад
Bọde Itapa, ogbologbo tọọgi tawọn ọlọpaa Ọṣun n wa ree o
Naijiria yoo dara ti awa ti a ti de Mẹka ri ba n ṣamulo ẹkọ ti a kọ nibẹ - Alhaja Agboọla
Просмотров 434 месяца назад
Naijiria yoo dara ti awa ti a ti de Mẹka ri ba n ṣamulo ẹkọ ti a kọ nibẹ - Alhaja Agboọla

Комментарии

  • @AnnaMarisax-x1g
    @AnnaMarisax-x1g 10 дней назад

    Oloriburuku omo ole I pray make you no come back again because you have killed alot of people in ilesha both village people 😢

  • @babatopeadebiyi9940
    @babatopeadebiyi9940 16 дней назад

    May his gentle soul enjoy eternal rest

  • @kingklemo7960
    @kingklemo7960 16 дней назад

    May his soul rest in peace

  • @PaulFate-o2o
    @PaulFate-o2o 23 дня назад

    ❤❤❤

  • @PaulFate-o2o
    @PaulFate-o2o 23 дня назад

    My king

  • @GideonOluwasegun-w6z
    @GideonOluwasegun-w6z 23 дня назад

    Adupe fun orire na

  • @musafathiat5495
    @musafathiat5495 23 дня назад

    Congratulations dad 🎉

  • @akinwaleolufemi9186
    @akinwaleolufemi9186 Месяц назад

    Ole ni gbogbo eyin oloselu wa.

  • @alhajisanusi6929
    @alhajisanusi6929 Месяц назад

    Nobody is closing it stop all this is only disallow heavy truck it card and bus so stop all this type of statement

  • @akinwaleolufemi9186
    @akinwaleolufemi9186 Месяц назад

    Honorable Baneek as usually.

  • @KassoumMouhamedi
    @KassoumMouhamedi 3 месяца назад

    Eleyiganopadadiajinigbepada

    • @Infinitesimal411
      @Infinitesimal411 3 месяца назад

      Shey koti ni ma jiniyingbe teleni. ? Apaniyan bi eran.

  • @olanrewajuenoch8869
    @olanrewajuenoch8869 3 месяца назад

    This is brutal. They doesn't deserve mercy from Nigerians.

  • @sunshinesm5657
    @sunshinesm5657 3 месяца назад

    Rally oriburuku ti e nse please send him to prison just for 1000 years.

  • @johnjanusek6953
    @johnjanusek6953 3 месяца назад

    Very funny man...in Arab countries they practice idol worshipping till today.

  • @olusegunayoola2312
    @olusegunayoola2312 3 месяца назад

    This man na werey. He say omo yahoo biza,biza😅😅😅😅

  • @babajideayanwale8697
    @babajideayanwale8697 3 месяца назад

    See whining from bode

  • @babajideayanwale8697
    @babajideayanwale8697 3 месяца назад

    Bode itapa oosha... Iku n bomorin Omo o fura

  • @babajideayanwale8697
    @babajideayanwale8697 3 месяца назад

    Were o Fe gba Idajo iku sugbon o le payan😅

  • @babajideayanwale8697
    @babajideayanwale8697 3 месяца назад

    Awon Apayan buruku

  • @twenty-foursevenchannel5434
    @twenty-foursevenchannel5434 3 месяца назад

    NO WAHALA........DEM GO PUT U WHERE U BELONG

  • @augustusstendeback4395
    @augustusstendeback4395 3 месяца назад

    See that woman yansh 😮😮😮😂

  • @richrich6950
    @richrich6950 3 месяца назад

    The government, politicians are destroying our youths using them as political thuggery and joint the cult for survival 😮

  • @OluwapelumyIsijolah
    @OluwapelumyIsijolah 3 месяца назад

    Agba oni tan Lorilee

  • @OluwapelumyIsijolah
    @OluwapelumyIsijolah 3 месяца назад

    I Love this valuable information.

  • @khunzo
    @khunzo 3 месяца назад

    bisa bisa

    • @papadem07
      @papadem07 3 месяца назад

      Bisa bisa indeed😂😂

  • @carolinetodd8338
    @carolinetodd8338 4 месяца назад

    😂😂 Bode just dey wine them 😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂😂Na God go punish you

  • @olajideoluwayomi6529
    @olajideoluwayomi6529 4 месяца назад

    Ẹyin ọdọmọde ẹ dẹ́kun àti ma sọ ara yín di irinṣẹ ibi lọ́wọ́ àwọn olóṣèlú

  • @oshooluwafemicharles7881
    @oshooluwafemicharles7881 4 месяца назад

    Grade 1 oloriburuku.

  • @lanreariwayo6416
    @lanreariwayo6416 4 месяца назад

    Crafty guy

  • @AdebayoGrace-e5i
    @AdebayoGrace-e5i 4 месяца назад

    😂

  • @famuyidesegun1610
    @famuyidesegun1610 4 месяца назад

    Hmmmmm

  • @olalerelukman9120
    @olalerelukman9120 6 месяцев назад

    The is has mental health challenge

  • @biolaforeign651
    @biolaforeign651 6 месяцев назад

    Ve😮 very nice man.....sen Kola ogunwale.....if only you know him you we understand.....may you live long

  • @adufelawal9487
    @adufelawal9487 8 месяцев назад

    Pelu sikioritii to daju ti Awon Fulani koni ledebe pelu Maalu won rara .

  • @adufelawal9487
    @adufelawal9487 8 месяцев назад

    Sebi Awon na ri bi Awon Fulani SE npa.awon eyan ninu Oko abi won ko gboni.

  • @adufelawal9487
    @adufelawal9487 8 месяцев назад

    Ki omo re na omo re gangan lo da ishe agbe sile ko waa gba Awon Eniyan si inu Oko agbe na sebi OUN na ri bi Awon Fulani SE na Awon eyan sinu Oko won . Tabi ki won wa Ile Ti otobi dada pelu Sabo to daju to keep Awon Fulani ko ni le de ibi Ile na rara . Ni gbogbo Ile Yoruba igba na ni away to mape ijoba to Dara ni ijoba Tinuubu nse .

  • @LolaFoluso
    @LolaFoluso 10 месяцев назад

    Kini latest news lori oro pasito kayode

    • @etiobatv
      @etiobatv 10 месяцев назад

      O ti wa lakolo ọlọpaa niluu Oṣogbo

  • @rafade8530
    @rafade8530 Год назад

    ALL ARE FAKE EXCUSES. THEY ARE NOT HAPPY THAT ADEDOYIN IS FOUND GUILTY.

  • @rafade8530
    @rafade8530 Год назад

    WE NOW KNOW THE RITUALISTS .EMERGENCY RICH PEOPLE AND POLITICIANS.

  • @rafade8530
    @rafade8530 Год назад

    ADEDOYIN PEOPLE ARE AT WORK. THEY ARE FIGHTING BACK. RITUALISTS UNITED.

  • @sulaimonlukmon4600
    @sulaimonlukmon4600 Год назад

    They are saying nonsense. Senator Mudasir Hussein is our man.

  • @olayiwola4k481
    @olayiwola4k481 Год назад

    Ilobu people like fighting with their neighbours town too much. Last two years you guys fought with Erin osun , now you're still fighting with ifon osun

  • @olayiwola4k481
    @olayiwola4k481 Год назад

    You guys are telling lies, am from osogbo, ifon is an historical town in osun state not ilobu, ifon have been there for longtime. Ilobu like troubles too much.

  • @akinwaleolufemi9186
    @akinwaleolufemi9186 Год назад

    Ni bo lowa nigbati Isiaka Adegboyega oyetola naa ko Corona palliative pamo fun Awon Ara llu Lati fi se lpolongo eto ldibo fun saa elekeji to fe lo oloselu ni gbogbo yin .

  • @awosanmifrancis7685
    @awosanmifrancis7685 Год назад

    Alh.Ayinde e ku ise ilu,otito ponbele ni ohun ti e so,iya n je osise feyinti onimodamoda.Olorun yo gba eto wa fun wa o.

  • @akinwaleolufemi9186
    @akinwaleolufemi9186 Год назад

    Medinat adesoye you're so competent watching from Doha Qatar

  • @akinwaleolufemi9186
    @akinwaleolufemi9186 Год назад

    We're you not the one sometimes said that Ademola Adeleke cannot become the governor and prophet Tibetan man proposed God disposed we shall see .

  • @ogunrindeadebisi
    @ogunrindeadebisi Год назад

    AYO NITI OMO OLORUN ❤😂

  • @BeejayElectric
    @BeejayElectric Год назад

    ❤️ 🌹 👏💪

  • @titilayoadedeji2016
    @titilayoadedeji2016 Год назад

    True Talk