- Видео 115
- Просмотров 730 256
OYEOLOHUN TV
Нигерия
Добавлен 22 апр 2020
Gbígbé àṣà àti ìṣe pẹ̀lú èdè Yorùbá lárugẹ ló jẹ wá lógún.
Ẹ lè kàn sí wa lórí:
*Instagram: oyeolohun_tv
*Tiktok: OYEOLOHUN_TV
*Facebook: Oyeolohun88
Gmail: oyeolohunnaa@gmail.com
Ẹ seun tí ẹ̀ ńtẹ́tí gbọ́ wa, ẹ le pè wá sí ẹ̀rọ ìbára ẹni sọ̀rọ̀ yìí 08069316812. Bí ẹ bá ní ohun láti bá wa sọ. Ire ni tiwa tẹ̀yin lọ́jọ́ gbogbo. Ooodabọọọ. 🙏
Ẹ lè kàn sí wa lórí:
*Instagram: oyeolohun_tv
*Tiktok: OYEOLOHUN_TV
*Facebook: Oyeolohun88
Gmail: oyeolohunnaa@gmail.com
Ẹ seun tí ẹ̀ ńtẹ́tí gbọ́ wa, ẹ le pè wá sí ẹ̀rọ ìbára ẹni sọ̀rọ̀ yìí 08069316812. Bí ẹ bá ní ohun láti bá wa sọ. Ire ni tiwa tẹ̀yin lọ́jọ́ gbogbo. Ooodabọọọ. 🙏
OGBOJU ODE || Alujonnu Eniyan ni baba mi, O ku to oore ogun ki o to fi aye sile, Alagbara ni...
#challenge #asayoruba #animals #love #asa #africa #africa #greenscreen #comedy #comment #cute #viralvideo #viralshorts #edeyorubarewa #subscribers #likes
Просмотров: 1 310
Видео
OGBOJU ODE || Aye nsare ju bi gbogbo wa ti lero lo, bi moba toju Eniyan tan ni mo to ma ngba nnkan..
Просмотров 1,6 тыс.19 часов назад
#love #asayoruba #animals #challenge #asa #africa #comedy #comment #cute #makemefamous #ogun #godofiron #god #ifa #viralvideo #subscribers #youtube
OGBOJU ODE || Alujonnu ni kii jeki ode ri omo eranko to yin ibon si gbe lopo igba ninu igbe...
Просмотров 3 тыс.28 дней назад
#love #asayoruba #challenge #obaofbeninvisitooniofife #animals #africa #asa #makemefamous #comedy #cute #viralvideo #comment #ifa #subscribe #subscribers
OGBOJU ODE || Awon Oogun Orisi Meta Kan Nbe Ti Eni Toba Pe Ara Re Ni Ogbontagi Ode Gbodo Ni Lowo...
Просмотров 2,3 тыс.Месяц назад
#love #asayoruba #africa #makemefamous #obaofbeninvisitooniofife #animals #cute #asa #comedy #comment #like #viralvideo #subscribers #isese #yoruba
OGBOJU ODE || Kodi Igbati Eniyan Balo Nnkan Ara Eniyan Ki O to Ri Ile-Aye Se, Ti Alujonnu...
Просмотров 2,6 тыс.2 месяца назад
#love #comedy #viralvideo #makemefamous #subscribe #asa #asayoruba #asayoruba #cute #obasolomoni #comment #africa #animals #like #followers
OGBOJU ODE || Iya Kan Yo Siwa Lojiji Nibiti A ti n Se Ise Lebira, O Funmi Ni Obi Agbara, Pupa ati...
Просмотров 4,7 тыс.2 месяца назад
#asayoruba #asa #comedy #funny #obasolomoni #tundeednut #makemefamous #subscriber #subscribemychannel #comment #followers #animals #love #africa #edeyorubarewa #edeyoruba
OGBOJU ODE || Alujonnu tele mi wale, Mofe pa eranko esuo, o ka ese kan soke.
Просмотров 3,9 тыс.3 месяца назад
#asayoruba #comedy #animals #funny #asa #makemefamous #love #africa #ifa #ogboninunchannel #ogun #egungun #mufasatundeednut
OGBOJU ỌDẸ || Ti Eniyan ba mọ ẹwọn Àlùjọ̀ǹnú Kosi Isẹ́ to ma ran wọn, ti wọn kòní jẹ́, Mo ranti...
Просмотров 9043 месяца назад
#ogun #africa #love #asa #comedy #subscribe #subscribers #asayoruba #funny #edeyorubarewa #cute #ifa
OGBOJU ODE || Ti Eniyan Bamo Ewon Alujonnu, Kosi ise to ma be won, tiwon koni je, Mo ranti ojo...
Просмотров 3,1 тыс.3 месяца назад
#folklore #ogun #asa #africa #africa #asayoruba #love #edeyorubarewa #animals #funny #funny #challenge #challenge #love #like #livestream
OGBOJU ODE || Gbogbo Awon Alujonnu, Ebora, Kosi eyi tole fi owo kan ise ti moba se.
Просмотров 3,2 тыс.4 месяца назад
#folklore #ogun #asa #africa #asayoruba #love #animals #edeyorubarewa #funny #challenge #hunter #ifa
OGBOJU ODE || Ojo ti mi o le gbagbe lojo ti mo to ipa ese Abami ekulu titi mofi sonu sinu igbo.
Просмотров 4,9 тыс.4 месяца назад
#asayoruba #folklore #ogun #edeyorubarewa #africa #africa #animals #asa #asa #folklore #animals #love #culture #culture #funny
AISUN ODUN EGUNGUN 2024 T'ILU TEDE.
Просмотров 3944 месяца назад
#edeyorubarewa #folklore #africa #asa #animals #asayoruba #love #animals #love #asayoruba #culture #funny #ifa
OGBOJU ODE || Odo ti eja inu re kii Jina ti won ba pa, ti won se e nilu Ago Amodu.
Просмотров 4,4 тыс.5 месяцев назад
#edeyorubarewa #africa #folklore #asa #animals #asayoruba #love #love #culture #funny #ifa #ogboninunogboninuntv
OGBOJU ODE || Mo Pade Alujonnu, O yira pada di Obinrin to ro aso dudu ati funfun ninu Aginju.
Просмотров 9 тыс.5 месяцев назад
#folklore #asa #africa #asayoruba #funny #edeyorubarewa #culture #edeyorubarewa #ifa #ogun #viralvideo #share
OGBOJU ODE || Ki nto gba ise tabi Ki won to gbe eniyan de odo mi, won a ti so iru isoro eni be funmi
Просмотров 5 тыс.5 месяцев назад
#africa #asa #asayoruba #culture #edeyorubarewa #ifa #ogun #viralvideo #yoruba #ogboninunchannel
OGBOJU ODE || Mo Pade Eranko Agbonrin to yirapada di Eniyan, O toro omi lowo mi...
Просмотров 59 тыс.6 месяцев назад
OGBOJU ODE || Mo Pade Eranko Agbonrin to yirapada di Eniyan, O toro omi lowo mi...
OGBOJU ODE || Alujonnu, Ebora ko je nnkan kan si emi, Alujonnu tan ina ehin si mi, Mo yin ibon si...
Просмотров 5 тыс.8 месяцев назад
OGBOJU ODE || Alujonnu, Ebora ko je nnkan kan si emi, Alujonnu tan ina ehin si mi, Mo yin ibon si...
OGBOJU ODE || Kosi Osanyin kankan Laye Mo, Iro loku, Aanu Ile yoruba se mi nitori enu loku...
Просмотров 7 тыс.8 месяцев назад
OGBOJU ODE || Kosi Osanyin kankan Laye Mo, Iro loku, Aanu Ile yoruba se mi nitori enu loku...
OGBOJU ODE || Emi ati Awon emi Airi, Ebora, jo ma nsere labe igi lapalapa lati igba kekere mi ni...
Просмотров 10 тыс.8 месяцев назад
OGBOJU ODE || Emi ati Awon emi Airi, Ebora, jo ma nsere labe igi lapalapa lati igba kekere mi ni...
OGBOJU ODE || Eniti Koni oogun, ti ko mo nnkan kan ko le losi inu aginju ti ebora, Efon, Ajanaku wa.
Просмотров 8 тыс.10 месяцев назад
OGBOJU ODE || Eniti Koni oogun, ti ko mo nnkan kan ko le losi inu aginju ti ebora, Efon, Ajanaku wa.
OGBOJU ODE || Alujonnu Ebora tan ina, o nto mi bo, O Niki nkuro loju ona awon...
Просмотров 7 тыс.11 месяцев назад
OGBOJU ODE || Alujonnu Ebora tan ina, o nto mi bo, O Niki nkuro loju ona awon...
OGBOJU ODE || Kosi Isoro Ti Ifa Kole Yanju Ti Babalawo Ba Gbo Ifa Dada Ti Kosi Fi Iro kun...
Просмотров 2,4 тыс.Год назад
OGBOJU ODE || Kosi Isoro Ti Ifa Kole Yanju Ti Babalawo Ba Gbo Ifa Dada Ti Kosi Fi Iro kun...
OGBOJU ODE || Won Ko i ti Bimi Saye Ti Won Ti Sope Omo To Nbe Ninu Iya Mi Wipe Ifa Ni...
Просмотров 5 тыс.Год назад
OGBOJU ODE || Won Ko i ti Bimi Saye Ti Won Ti Sope Omo To Nbe Ninu Iya Mi Wipe Ifa Ni...
OGBOJU ỌDẸ || Ẹbọra Alujọnnu wa bami ninu oko, o sọ asiri funmi, A sidi ọrẹ di oni oloni...
Просмотров 17 тыс.Год назад
OGBOJU ỌDẸ || Ẹbọra Alujọnnu wa bami ninu oko, o sọ asiri funmi, A sidi ọrẹ di oni oloni...
OGBOJU ODE || Aja gbemi lo fun ojo meje, Mi o mo bi Aye ni mowa bi orun...
Просмотров 8 тыс.Год назад
OGBOJU ODE || Aja gbemi lo fun ojo meje, Mi o mo bi Aye ni mowa bi orun...
OGBOJU ODE|| Awọn Iwin ti mo pa to mẹẹdogun, ati ọ̀run ni moti gbe agbára mi wa...
Просмотров 8 тыс.Год назад
OGBOJU ODE|| Awọn Iwin ti mo pa to mẹẹdogun, ati ọ̀run ni moti gbe agbára mi wa...
OGBOJU ỌDẸ || Baba mi pa Iwin Àlùjọ̀ǹnú, O gbe orí rẹ wasi ile, O nbẹ ninu iyara...
Просмотров 32 тыс.Год назад
OGBOJU ỌDẸ || Baba mi pa Iwin Àlùjọ̀ǹnú, O gbe orí rẹ wasi ile, O nbẹ ninu iyara...
OGBOJU ODE|| Onílù oba yirapada di okuta, ọba yirapada di olufa, ó fà wọnú igbó lọ.
Просмотров 13 тыс.Год назад
OGBOJU ODE|| Onílù oba yirapada di okuta, ọba yirapada di olufa, ó fà wọnú igbó lọ.
From Car Hire and Hire to Driving Toyota Siena. Glory Be To God Almighty and You all my supporters.
Просмотров 893Год назад
From Car Hire and Hire to Driving Toyota Siena. Glory Be To God Almighty and You all my supporters.
OGBOJU ODE|| Wọn ti ran Sango si mi ri bíi ẹẹmẹta sugbọn Ògún ko jẹ ki o le bami ja.
Просмотров 15 тыс.Год назад
OGBOJU ODE|| Wọn ti ran Sango si mi ri bíi ẹẹmẹta sugbọn Ògún ko jẹ ki o le bami ja.
Amì ase ❤❤❤✅🙏🙏🙏
OyeOlorunTV’s introduction and flute(kàkàkí) are very appropriate with every episode. Words and praise need confirmation by both men and spirits. We hear Agoro’s words and àwon àlùjònnú(spirits) hear kàkàkí’s rendition of the words being said. Àwa omo adáríhunrun are in unique position to hear and understand spoken words as well as the flute! Good job, ę ó máa mòn se o!
Nice job 👍
Oye olohun bawo ni o
Kudos to you sir
I trust you sir omo agoro
Weldone sir
I greet you sir
Eku eto sir
Very educative program
Weldone sir
Eku igbe asa yoruba ga sir
Olohun yoma Palo atabo yin mo sir
Oluwo agbamunigogo alabenu asasi omo ode no emina osooo gun o
Thank you my brother
Weldone my brother Oyeolohun
Oyeolohun kuse o olorun ama fu e se
Good program weldone sir
Hope you will be continue to post like this sir weldone o
Amin oooo ooo eku eto
Igboho Osha
Weldone sir
Eku ise takuntakun Oyeolohun
Kudos to you sir
Where is Tede? Can I have babas number please?
He's the father of the anchor
Akiiti lo le ja o, ija lo le ja (2ce), o gbe para o fi da, ija lo le ja...🎵🎶💃
Iya mi oooo😂
The chief hunter's voice is very distinct and clear👌
Thanks Ìyá mi KUDIRAT ✌️
This man Oluode is powerful ❤
🎉❤
Thanks My Wonderful person, you are one in a million ✌️
I love your advice ❤️
Thanks ✌️
Respect, wow great hunter. Love you more sir
Amì ase ❤ Boda mi nurudine edumare awapeluyin
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, Aburú ó kéré ó tóbi kòní wọlé tọ yín, Ẹ seun pupọ ✌️
Very educative program weldone sir
Thanks My brother ✌️
Weldone Oyeolohun Mo ki babaawo ooo
Ẹ seun ma, BABAWO a gbọ ooo✌️
Wow🎉
Thanks ✌️
Weldone sir I always learn one or two things on your program
Thanks ✌️
❤❤❤
Thanks✌️
Very educative program weldone sir
Ẹ seun Ẹ̀gbọ́n mi ✌️
I always enjoy your program sir may God bless your hustle
Much appreciated, Olódùmarè kòní jẹ́kí ẹ dààmú láyé yín ✌️
Oye olohun omo agoro Eku ise o
Ẹ seun Bàbá mi, àwa náà kọ Olódùmarè ni o✌️
Bro you good weldone
Thanks My brother ✌️
Weldone sir
Thanks My brother ✌️
Eku ise takuntakun sir
Ẹ seun púpọ̀ ✌️
Koni suyin koni reyin lagbara olorun
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, àti ẹ̀yin náà lágbára Olódùmarè ✌️
May god continue to be protect you and your crew
Amen sir, ojú kìí ti iná alẹ́, ojú kòní ti yin láṣẹ Èdùmàrè ✌️
You are doing well my brother
Thanks bro ✌️
Yooma juyin se ooo
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, àsetì kìí bá ọjọ́ kí ọjọ́ kó má yọ, àsetì kòní ba yín ✌️
Eku ise opolo baba Olodumare koni pada leyin yin
Àmín àṣẹ Èdùmàrè, àti ẹ̀yin náà lágbára Olódùmarè ✌️ Ẹ seun
🥰🥰🥰
Akanni ọ̀gọ̀, Thanks ✌️